ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Dáníẹ́lì

      • Àwọn ará Bábílónì dó ti Jerúsálẹ́mù (1, 2)

      • Wọ́n dìídì dá àwọn ọmọ ọba tí wọ́n kó lẹ́rú lẹ́kọ̀ọ́ (3-5)

      • Wọ́n dán ìṣòtítọ́ àwọn Hébérù mẹ́rin wò (6-21)

Dáníẹ́lì 1:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:4; Jer 22:18, 19; 36:30
  • +Di 28:49, 50; 2Ọb 24:1; 2Kr 36:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jeremáyà, ojú ìwé 24

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 18-19, 31-32

Dáníẹ́lì 1:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tẹ́ńpìlì.”

  • *

    Ìyẹn, Babilóníà.

  • *

    Tàbí “tẹ́ńpìlì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:24
  • +Jẹ 10:9, 10
  • +2Kr 36:7; Ẹsr 1:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jeremáyà, ojú ìwé 24

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 32-33

Dáníẹ́lì 1:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 20:16, 18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 33

Dáníẹ́lì 1:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọmọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 1:17, 20; 5:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 7, 33-34

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1997, ojú ìwé 15

    11/1/1992, ojú ìwé 13-14

Dáníẹ́lì 1:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “bọ́ wọn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2005, ojú ìwé 27

    11/1/1992, ojú ìwé 13-14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 34-35

Dáníẹ́lì 1:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ.”

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ọlọ́run Ni Onídàájọ́ Mi.”

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Jèhófà Ti Ṣojúure.”

  • *

    Ó ṣeé ṣe kó túmọ̀ sí “Ta Ló Dà Bí Ọlọ́run?”

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Jèhófà Ti Ṣèrànwọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 2:48; 5:13, 29
  • +Da 2:17, 18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 33-34

Dáníẹ́lì 1:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, orúkọ àwọn ará Bábílónì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 4:8; 5:12
  • +Da 2:49; 3:12, 28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2016, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 34-36

Dáníẹ́lì 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 36-39

Dáníẹ́lì 1:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “inú rere.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:49, 50; Sm 106:44, 46

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 39

Dáníẹ́lì 1:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọmọ.”

  • *

    Ní Héb., “orí mi.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2007, ojú ìwé 19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 39

Dáníẹ́lì 1:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2007, ojú ìwé 19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 39-40

Dáníẹ́lì 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2007, ojú ìwé 18

    7/15/2005, ojú ìwé 27-28

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 40

Dáníẹ́lì 1:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọmọ.”

Dáníẹ́lì 1:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lọ́ràá.”

  • *

    Ní Héb., “ọmọ.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2007, ojú ìwé 18

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 40-41

Dáníẹ́lì 1:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 41-42

Dáníẹ́lì 1:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọmọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 1:20; 4:9; 5:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 42

Dáníẹ́lì 1:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 1:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 42-43

Dáníẹ́lì 1:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 1:3, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 43

Dáníẹ́lì 1:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 2:2; 4:7; 5:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 43-44

Dáníẹ́lì 1:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 6:28; 10:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 45

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/1997, ojú ìwé 15

Àwọn míì

Dán. 1:12Kr 36:4; Jer 22:18, 19; 36:30
Dán. 1:1Di 28:49, 50; 2Ọb 24:1; 2Kr 36:5, 6
Dán. 1:2Ais 42:24
Dán. 1:2Jẹ 10:9, 10
Dán. 1:22Kr 36:7; Ẹsr 1:7
Dán. 1:32Ọb 20:16, 18
Dán. 1:4Da 1:17, 20; 5:11, 12
Dán. 1:6Da 2:48; 5:13, 29
Dán. 1:6Da 2:17, 18
Dán. 1:7Da 2:49; 3:12, 28
Dán. 1:7Da 4:8; 5:12
Dán. 1:91Ọb 8:49, 50; Sm 106:44, 46
Dán. 1:17Da 1:20; 4:9; 5:11, 12
Dán. 1:18Da 1:5
Dán. 1:19Da 1:3, 6
Dán. 1:20Da 2:2; 4:7; 5:8
Dán. 1:21Da 6:28; 10:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Dáníẹ́lì 1:1-21

Dáníẹ́lì

1 Ní ọdún kẹta àkóso Jèhóákímù+ ọba Júdà, Nebukadinésárì ọba Bábílónì wá sí Jerúsálẹ́mù, ó sì pàgọ́ tì í.+ 2 Nígbà tó yá, Jèhófà fi Jèhóákímù ọba Júdà lé e lọ́wọ́,+ pẹ̀lú àwọn ohun èlò kan ní ilé* Ọlọ́run tòótọ́, ó sì kó wọn wá sí ilẹ̀ Ṣínárì*+ sí ilé* ọlọ́run rẹ̀. Ó kó àwọn ohun èlò náà sínú ilé ìṣúra ọlọ́run rẹ̀.+

3 Ọba wá pàṣẹ fún Áṣípénásì olórí òṣìṣẹ́ ààfin rẹ̀ pé kó mú lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* wá, títí kan àwọn ọmọ ọba àti ọmọ àwọn èèyàn pàtàkì.+ 4 Kí wọ́n jẹ́ ọ̀dọ́* tí kò ní àbùkù kankan, tí ìrísí wọn dáa, tí wọ́n ní ọgbọ́n, ìmọ̀ àti òye,+ tí wọ́n sì lè ṣiṣẹ́ ní ààfin ọba. Kí ó kọ́ wọn ní èdè àwọn ará Kálídíà àti bí wọ́n ṣe ń kọ̀wé. 5 Bákan náà, ọba ní kí wọ́n máa fún wọn ní oúnjẹ lójoojúmọ́, lára oúnjẹ aládùn tí ọba ń jẹ àti lára wáìnì tó ń mu. Wọ́n máa fi ọdún mẹ́ta dá wọn lẹ́kọ̀ọ́,* tí ọdún náà bá sì ti pé, wọ́n máa bẹ̀rẹ̀ sí í bá ọba ṣiṣẹ́.

6 Àwọn kan wà lára wọn tí wọ́n wá látinú ẹ̀yà* Júdà: Dáníẹ́lì,*+ Hananáyà,* Míṣáẹ́lì* àti Asaráyà.*+ 7 Àgbà òṣìṣẹ́ láàfin sì fún wọn ní orúkọ;* ó pe Dáníẹ́lì ní Bẹtiṣásárì,+ ó pe Hananáyà ní Ṣádírákì, ó pe Míṣáẹ́lì ní Méṣákì, ó sì pe Asaráyà ní Àbẹ́dínígò.+

8 Àmọ́ Dáníẹ́lì pinnu lọ́kàn rẹ̀ pé òun ò ní fi oúnjẹ aládùn tí ọba ń jẹ àti wáìnì tó ń mu sọ ara òun di aláìmọ́. Torí náà, ó ní kí àgbà òṣìṣẹ́ láàfin gba òun láyè kí òun má bàa fi àwọn nǹkan yìí sọ ara òun di aláìmọ́. 9 Ọlọ́run tòótọ́ sì mú kí àgbà òṣìṣẹ́ láàfin fi ojúure* àti àánú hàn sí Dáníẹ́lì.+ 10 Àmọ́ àgbà òṣìṣẹ́ láàfin sọ fún Dáníẹ́lì pé: “Ẹ̀rù olúwa mi ọba ń bà mí, ẹni tó ti ṣètò jíjẹ àti mímu yín. Tó bá wá rí i pé ìrísí yín burú ju ti àwọn ọ̀dọ́* yòókù tí ẹ jọ jẹ́ ojúgbà ńkọ́? Ẹ máa jẹ́ kí ọba dá mi* lẹ́bi.” 11 Àmọ́ Dáníẹ́lì sọ fún ẹni tí àgbà òṣìṣẹ́ láàfin yàn láti máa tọ́jú Dáníẹ́lì, Hananáyà, Míṣáẹ́lì àti Asaráyà pé: 12 “Jọ̀ọ́, fi ọjọ́ mẹ́wàá dán àwa ìránṣẹ́ rẹ wò, kí o máa fún wa ní nǹkan ọ̀gbìn jẹ, kí o sì máa fún wa ní omi mu; 13 kí o wá fi ìrísí wa wé ti àwọn ọ̀dọ́* tó ń jẹ oúnjẹ aládùn tí ọba ń jẹ, lẹ́yìn náà, bí o bá ṣe rí àwa ìránṣẹ́ rẹ sí ni kí o ṣe sí wa.”

14 Ó wá gba ohun tí wọ́n sọ, ó sì fi ọjọ́ mẹ́wàá dán wọn wò. 15 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́wàá, ìrísí wọn dáa, ara wọn sì le* ju ti gbogbo àwọn ọ̀dọ́* tó ń jẹ oúnjẹ aládùn tí ọba ń jẹ. 16 Torí náà, ẹni tó ń tọ́jú wọn máa ń gbé oúnjẹ aládùn wọn àti wáìnì wọn kúrò, ó sì máa ń fún wọn ní nǹkan ọ̀gbìn. 17 Ọlọ́run tòótọ́ fún àwọn ọ̀dọ́* mẹ́rin yìí ní ìmọ̀ àti òye nínú oríṣiríṣi ìkọ̀wé àti ọgbọ́n; ó sì fún Dáníẹ́lì ní òye láti túmọ̀ onírúurú ìran àti àlá.+

18 Nígbà tó tó àkókò tí ọba sọ pé kí wọ́n kó wọn wá,+ àgbà òṣìṣẹ́ láàfin kó wọn wá síwájú Nebukadinésárì. 19 Nígbà tí ọba bá wọn sọ̀rọ̀, kò sí ìkankan nínú wọn tó dà bíi Dáníẹ́lì, Hananáyà, Míṣáẹ́lì àti Asaráyà;+ wọ́n sì ń bá ọba ṣiṣẹ́. 20 Nínú gbogbo ọ̀rọ̀ tí ọba bi wọ́n, tó gba ọgbọ́n àti òye, ó rí i pé wọ́n fi ìlọ́po mẹ́wàá dáa ju gbogbo àwọn àlùfáà onídán àti àwọn pidánpidán+ tó wà ní gbogbo ibi tó jọba lé lórí. 21 Dáníẹ́lì sì wà níbẹ̀ títí di ọdún àkọ́kọ́ Ọba Kírúsì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́