ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 35
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìsíkíẹ́lì

      • Sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí àwọn òkè Séírì (1-15)

Ìsíkíẹ́lì 35:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 32:3; Di 2:5
  • +Jer 49:8; Ida 4:22; Isk 25:8, 9; Ọbd 1

Ìsíkíẹ́lì 35:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 25:12, 13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2017, ojú ìwé 4

Ìsíkíẹ́lì 35:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 3:19; Mal 1:3

Ìsíkíẹ́lì 35:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 27:41; Emọ 1:11
  • +Sm 137:7; Ọbd 10

Ìsíkíẹ́lì 35:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìtàjẹ̀sílẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ọbd 15
  • +Isk 25:14

Ìsíkíẹ́lì 35:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 25:13

Ìsíkíẹ́lì 35:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 49:17, 18; Isk 25:13; Mal 1:4

Ìsíkíẹ́lì 35:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 36:5; Ọbd 13

Ìsíkíẹ́lì 35:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 1:11

Ìsíkíẹ́lì 35:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “bí oúnjẹ.”

Ìsíkíẹ́lì 35:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ọbd 3

Ìsíkíẹ́lì 35:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ida 4:21; Ọbd 12, 15
  • +Ais 34:5; Isk 25:12, 13; 36:5

Àwọn míì

Ìsík. 35:2Jẹ 32:3; Di 2:5
Ìsík. 35:2Jer 49:8; Ida 4:22; Isk 25:8, 9; Ọbd 1
Ìsík. 35:3Isk 25:12, 13
Ìsík. 35:4Joẹ 3:19; Mal 1:3
Ìsík. 35:5Jẹ 27:41; Emọ 1:11
Ìsík. 35:5Sm 137:7; Ọbd 10
Ìsík. 35:6Ọbd 15
Ìsík. 35:6Isk 25:14
Ìsík. 35:7Isk 25:13
Ìsík. 35:9Jer 49:17, 18; Isk 25:13; Mal 1:4
Ìsík. 35:10Isk 36:5; Ọbd 13
Ìsík. 35:11Emọ 1:11
Ìsík. 35:13Ọbd 3
Ìsík. 35:15Ida 4:21; Ọbd 12, 15
Ìsík. 35:15Ais 34:5; Isk 25:12, 13; 36:5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ìsíkíẹ́lì 35:1-15

Ìsíkíẹ́lì

35 Jèhófà tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ọmọ èèyàn, yíjú rẹ sí agbègbè olókè Séírì,+ kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí rẹ̀.+ 3 Sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Èmi yóò bá ọ jà, ìwọ agbègbè olókè Séírì, èmi yóò sì na ọwọ́ mi kí n lè fìyà jẹ ọ́, kí n sì sọ ilẹ̀ rẹ di ahoro.+ 4 Èmi yóò sọ àwọn ìlú rẹ di àwókù, wàá sì di ahoro;+ ìwọ yóò sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà. 5 Torí pé ìwọ ò yéé kórìíra+ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, tí o sì fà wọ́n lé idà lọ́wọ́ nígbà tí àjálù dé bá wọn, nígbà tí wọ́n jẹ ìyà ìkẹyìn.”’+

6 “‘Torí náà, bí mo ti wà láàyè,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘èmi yóò mú kí wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ rẹ sílẹ̀, ikú* yóò sì lépa rẹ.+ Nítorí pé o kórìíra ẹ̀jẹ̀, ikú yóò lépa rẹ.+ 7 Màá mú kí agbègbè olókè Séírì di ahoro,+ èmi yóò sì pa ẹnikẹ́ni tó bá ń kọjá lọ nínú rẹ̀ àti ẹnikẹ́ni tó bá ń pa dà bọ̀. 8 Èmi yóò fi òkú àwọn tí wọ́n pa kún àwọn òkè rẹ̀; àwọn tí wọ́n sì fi idà pa yóò ṣubú sórí àwọn òkè rẹ kéékèèké, sínú àwọn àfonífojì rẹ àti sínú gbogbo omi rẹ tó ń ṣàn. 9 Èmi yóò sọ ọ́ di ahoro títí láé, wọn ò sì ní gbé inú àwọn ìlú rẹ;+ ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’

10 “Torí o sọ pé, ‘Orílẹ̀-èdè méjì yìí àti ilẹ̀ méjì yìí yóò di tèmi, méjèèjì á sì di ohun ìní wa,’+ bó tiẹ̀ jẹ́ pé Jèhófà fúnra rẹ̀ wà níbẹ̀, 11 ‘torí náà, bí mo ti wà láàyè,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘bí o ṣe bínú sí wọn, tí o sì jowú wọn torí pé o kórìíra wọn ni èmi náà yóò ṣe sí ọ;+ màá sì jẹ́ kí wọ́n mọ̀ mí nígbà tí mo bá dá ọ lẹ́jọ́. 12 Ẹ ó wá mọ̀ pé èmi Jèhófà ti gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tí kò dáa tí ẹ sọ nípa àwọn òkè Ísírẹ́lì pé: “Wọ́n ti di ahoro, wọ́n sì ti fi wọ́n fún wa ká lè jẹ wọ́n run.”* 13 Ẹ fi ìgbéraga sọ̀rọ̀ sí mi, ẹ sì sọ̀rọ̀ sí mi gan-an.+ Gbogbo rẹ̀ ni mo gbọ́.’

14 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Inú gbogbo ayé yóò dùn nígbà tí mo bá sọ yín di ahoro. 15 Bí inú yín ṣe dùn nígbà tí ogún ilé Ísírẹ́lì di ahoro, bẹ́ẹ̀ ni màá ṣe sí yín.+ Ìwọ yóò di ahoro, ìwọ agbègbè olókè Séírì, àní gbogbo Édómù;+ wọ́n á sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́