Ojú ìwé 2
Ta Ni O Lè Gbẹ́kẹ̀ Lé? 3-10
Àwọn ènìyàn púpọ̀ sí i ń rí i pé ó ṣòro láti gbẹ́kẹ̀ lé àwọn ẹlòmíràn. Èé ṣe? Báwo ni a ṣe lè yẹra fún gbígbẹ́kẹ̀ wa lórí asán?
Matterhorn Òkè Ńlá Aláìlẹ́gbẹ́ 16
Ṣíṣàyẹ̀wò ọ̀kan lára àwọn òkè ńlá tí ó ṣàjèjì jù lọ lórí ilẹ̀ ayé.
Ìwà Àìlèkóra-Ẹni-Níjàánu—Ó Ha Ń Ṣàkóso Ìgbésí Ayé Rẹ Bí? 20
Báwo ni ènìyàn ṣe lè borí ìwà tí a kò fẹ́, tí ń sọni dìdàkudà yìí?