Ojú ìwé 2
Ìṣòro Wíwá Ibi Ìsádi—Yóò Ha Dópin Láé Bí? 3-11
A ti fipá mú àràádọ́ta ọ̀kẹ́ ènìyàn láti sá lọ. Báwo ni ìgbésí ayé ṣe rí fún olùwá-ibi-ìsádi kan? Èé ṣe tí ìṣòro náà fi ń burú sí i? Kí ni ojútùú rẹ̀?
Ó Ha Yẹ Kí N Máa Ṣe Àwọn Eré Àṣedárayá Orí Kọ̀m̀pútà Tàbí Fídíò Bí? 12
Àwọn eré àṣedárayá orí kọ̀m̀pútà àti fídíò dà bí ohun amóríyá tí kò lè ṣèpalára. Ìwọ́ ha mọ ìpalára tí wọ́n lè ṣe bí? Ìwọ yóò ha fi ọgbọ́n ṣe yíyàn bí?
Rọ́bà Kíkọ—Iṣẹ́ Kan Tí Ó Kan Ìgbésí Ayé Rẹ 18
A ń fi rọ́bà ṣe ẹgbẹẹgbẹ̀rún nǹkan. Ibo ló ti wá, kí ló sì mú kí ó wúlò tó bẹ́ẹ̀?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ẹ̀yìn ìwé: Albert Facelly/Sipa Press