Ojú ìwé 2
Ìsín Ha Ń Lọ Sópin Rẹ̀ Bí? 3-9
Pípọ̀ tí ìgbàgbọ́ ìsìn ń pọ̀ sí i jákèjádò ayé lẹ́nu àìpẹ́ yìí jẹ́ ìrísí ìtànjẹ nípa ohun tí ń bẹ lọ́jọ́ iwájú fún ìsìn ní ti gidi. Kí ni Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀?
Kí N Lè Bá Ọmọ Mi Sọ̀rọ̀, Mo Kọ́ Èdè Míràn 10
Ìyá kan sọ ìpèníjà tí ó dojú kọ lẹ́yìn tí ó mọ̀ pé ọmọ rẹ̀ dití.
Fọ́tò—Bí O Ṣe Lè Yà Á Dáradára 22
Nígbà wo ni o ya fọ́tò kan kẹ́yìn? Ǹjẹ́ ó dára? Bí ó ṣe rí tẹ́ ọ lọ́rùn bí? Amọṣẹ́dunjú kan fúnni ní àwọn ìmọ̀ràn dáradára díẹ̀.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Àwọn ọwọ́: Drawings of Albrecht Dürer/Dover Publications, Inc.