Ojú ìwé 2
Ó Ha Yẹ Kí O Máa Kàn sí Ilẹ̀ Ọba Ẹ̀mí Bí? 3-10
Àwọn ènìyàn níbi gbogbo ń gbìyànjú láti kàn sí ilẹ̀ ọba ẹ̀mí. Wọ́n ń fẹ́ mọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ iwájú. Wọ́n ń wá ìtọ́sọ́nà nípa àwọn ìṣòro ìgbésí ayé ojoojúmọ́. Ó ha ṣeé ṣe ní ti gidi láti kàn sí ilẹ̀ ọba ẹ̀mí bí? Àwọn wo ní ń gbé ibẹ̀? Ó ha yẹ kí o gbìyànjú láti kàn sí wọn bí?
Mímú Èrò Òdì Nípa Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kúrò 18
Bí àlejò olùbánisọ̀rọ̀ kan ṣe ṣàṣeparí èyí níwájú Ẹgbẹ́ Rotary kan ní San Francisco, California.
Àwọn Alárìnkiri àti Ìlàkàkà Wọn Láti Dòmìnira 24
Kí ló mú kí àwọn ènìyàn ẹlẹ́mìí ìsìn wọ̀nyí fẹ̀mí wewu ìrìn àjò gígùn, tí ń tánni lókun kan, ní líla òkun tí ó léwu kọjá pẹ̀lú ọkọ̀ kékeré kan?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Harper’s Encyclopædia of United States History