Ojú ìwé 2
Wíwá Ohun Àṣenajú Gbígbámúṣé 3-10
Púpọ̀ lára àwọn ohun àṣenajú lónìí ló kún fún ìwà ipá àti ìbálòpọ̀. Ìwọ ha ń wá ohun kan tí ó túbọ̀ bójú mu bí? Ibo ni o ti lè rí ohun àṣenajú gbígbámúṣé?
Ilé Ìwòran Orin Aláré Nínú Igbó Kìjikìji 14
Kí ni ilé ìwòran orin aláré ń ṣe nínú igbó kìjikìji tí ó tóbi jù lọ lágbàáyé?
Ọlọ́run Yóò Ha Máa Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Mi Nìṣó Bí? 18
Nígbà tí o bá ń ní ìṣòro, o lè lérò pé Ọlọ́run jìnnà sí ọ. Àmọ́, ṣé ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ní gidi nìyẹn bí?