Page Two 2
Àṣà Ìbálòpọ̀ Ohun Tí Ìṣarasíhùwà Tí Ń Yí Pa Dà Túmọ̀ Sí 3-10
Ìbálòpọ̀ lẹ́yìn òde ìgbéyàwó ti sábà ń múni pàdánù iyì ara ẹni, ìlera, àti ìbátan ẹni pẹ̀lú Ọlọ́run lọ́nà púpọ̀. Ṣùgbọ́n ìbẹ̀rù àrùn AIDS ha ti yí ìṣarasíhùwà àwọn ènìyàn pa dà bí?
Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Kí O Ṣàkóso Ìbínú Rẹ? 18
Bí ìbúgbàù òkè ayọnáyèéfín kan, ìbínú tí a kò ṣàkóso lè pa ìwọ àti àwọn mìíràn pẹ̀lú lára.
Singapore—Ọ̀ṣọ́ Iyebíye Ilẹ̀ Éṣíà Tí Wọ́n Bà Jẹ́ 21
Ẹwà ìrísí Singapore ha bá àkọsílẹ̀ tí ó ní nípa ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn mu bí?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Saul Attempts the Life of David/The Doré Bible Illustrations/Dover Publications, Inc.