Ojú ìwé 2
Ìkórìíra—Èé Ṣe Tí Ó Fi Pọ̀ Tó Bẹ́ẹ̀? Ìfẹ́—Èé Ṣe Tí Ó Fi Kéré Tó Bẹ́ẹ̀? 3-11
Ẹ wo bí ìgbésí ayé ṣe lè gbádùn mọ́ni tó nígbà tí a bá wà láàárín àwọn ènìyàn tí a nífẹ̀ẹ́! Síbẹ̀, ìfẹ́ ṣọ̀wọ́n gidigidi nínú ayé òde òní. Èé ṣe tí ìríra fi gbòde kan? Èyí yóò ha yí pa dà láé bí?
Kilimanjaro—Ibi Gíga Jù Lọ ní Áfíríkà 14
Kilimanjaro, òkè ńlá kan tí òjò dídì bo orí rẹ̀ ní ilẹ̀ Áfíríkà olóoru, lókìkí nítorí ẹwà rẹ̀ títayọ àti gíga rẹ̀ kíkàmàmà.
Àrùn RSD—Àrùn Ríronilára Kan Tí Ń Rúni Lójú 20
Àrùn RSD (Àrùn Ìṣiṣẹ́gbòdì Iṣan Amúnimọ̀rora) jẹ́ àrùn ríronilára kan. Kí ni alárùn náà lè ṣe?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Tina Gerson/Los Angeles Daily News