Ojú ìwé 2
Ṣọ́ra fún Àwọn Gbájú-Ẹ̀! 3-10
Oníjìbìtì gbígbọ́nféfé, tí ń kóni nífà, tí ó sì ń tanni jẹ ni wọ́n. Ṣọ́ra—ó lè jẹ́ ìwọ ni yóò kàn láti kó sọ́wọ́ wọn! Báwo ni wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́? Kí ni o lè ṣe láti dáàbò bo ara rẹ?
Cheetah —Ẹranko Ẹ̀yà Ológbò Tó Yára Jù Lọ 15
Kí ló ń jẹ́ kí arẹwà alámì tóótòòtó lára yìí fẹ́ nílẹ̀ tó bẹ́ẹ̀? Ta ni ọ̀tá bíburú jù lọ tí ẹranko cheetah ní?
Agbára Ìgbọ́ròó Rẹ —Ẹ̀bùn Tí Ó Yẹ Kí O Ṣìkẹ́ 21
Agbára ìgbọ́ròó rẹ jẹ́ ọ̀nà pàtàkì fún níní àjọṣe pẹ̀lú ohun tí ń lọ láyìíká rẹ̀. O ha fọwọ́ yẹpẹrẹ mú un bí?