Ojú ìwé 2
Ikọ́ Ẹ̀gbẹ—Panipani Tó Pa Dà Wá 3-9
Kí ló dé tí àrùn yí kò yé pọ́n aráyé lójú? Báwo ni o ṣe lè dáàbò bo ara rẹ? A óò ha ṣẹ́gun rẹ̀ láé bí?
Iṣẹ́ Rẹ Ń Sú Ọ Bí? 10
Iṣẹ́ sábà ń jẹ́ ohun tí a ń ṣe ní àṣetúnṣe. Kí ni a lè ṣe láti mú kí ó túbọ̀ tẹ́ni lọ́rùn?
Moscow Àjọ̀dún Àádọ́talélẹ́gbẹ̀rin Rẹ̀ 13
Àwọn ìpọ́njú wo ni ó ti forí tì? Àwọn ìyípadà wo ni ó ti ṣẹlẹ̀ láìpẹ́?
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
X ray: © SPL/Photo Researchers