Ojú ìwé 2
Nígbà Tí Àwọn Ọmọ Bá Fi Ilé Sílẹ̀ 3-12
Bópẹ́bóyá, púpọ̀ àwọn ọmọ yóò fi ilé sílẹ̀. Báwo ni àwọn òbí ṣe lè múra àwọn ọmọ wọn sílẹ̀ de ọjọ́ tí wọn yóò fi ilé sílẹ̀ lọ máa dá gbé? Bí àwọn ọmọ bá sì ti gbé ìgbésẹ̀ yí, báwo ni àwọn òbí ṣe lè kojú àìsínílémọ́ wọn?
Bí Mo Ṣe Kojú Ìkólòlò 13
Akólòlò kan ṣàlàyé àwọn ìṣòro tí ó ti ní láti ìbẹ̀rẹ̀ ìgbà ọmọdé rẹ̀.
Georgia—Ogún Àtayébáyé Kan Tí A Pa Mọ́ 24
Orílẹ̀-èdè kan tí ó lẹ́wà, tí àwọn ènìyàn kan níbẹ̀ ń gbé tó 100 ọdún àti jù bẹ́ẹ̀ lọ láyé!
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Pat O’Hara/Corbis