Ojú ìwé 2
Bí Ẹnì Kejì Wa Nínú Ìgbéyàwó Bá Hùwà Àìṣòótọ́ 3-12
Báwo ló ṣe ń rí lára àwọn tí ọ̀ràn yìí ń ṣẹlẹ̀ sí? Ǹjẹ́ ó yẹ kí a gbìyànjú láti yanjú ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹnì kejì wa tó ṣe panṣágà? Ǹjẹ́ jíjáwèé ìkọ̀sílẹ̀ ni yíyàn tó bọ́gbọ́n mu?
Èé Ṣe Tí Èrò Bí Mo Ṣe Tóbi Tó Fi Gbà Mí Lọ́kàn? 13
Wọ́n Lé Wa Kúrò Nílùú Lọ sí Siberia! 16
Kà nípa ìdílé kan tó la ọ̀pọ̀ ọdún já ní oko ẹrú ní Siberia, kí o sì mọ̀ nípa bí ìgbàgbọ́ wọn nínú Ọlọ́run ṣe mẹ́sẹ̀ wọn dúró.