Ojú ìwé 2
Ọ̀rúndún Ogún—Àwọn Ọdún Ìyípadà Pípeléke 3-12
Ọ̀pọ̀ ìyípadà mánigbàgbé ló ṣẹlẹ̀ ní ọ̀rúndún ogún. Àmọ́, àwọn èèyàn lápapọ̀ ò kọbi ara sí ọ̀kan lára àwọn ìyípadà tó ṣe pàtàkì jù lọ. Kí ni ìyípadà ọ̀hún?
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Túbọ̀ Túra Ká? 21
Ṣé ó dà bíi pé ojú máa ń tì ọ́? Wo àwọn àbá díẹ̀ tó lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti borí ìtìjú.
Ojú Ìwòye Bíbélì 24
Ǹjẹ́ àwọn ọba mẹ́ta bẹ Jésù wò ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù?