Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
March 8, 2004
Ìrọ́kẹ̀kẹ̀ Ogun—Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Ṣóòótọ́ Ni?
Kí ló dé tí ogun ọ̀gbálẹ̀gbáràwé ń bà wá lẹ́rù títí dòní olónìí? Àwọn wo ló ń gbára dì fún un? Ǹjẹ́ ó tiẹ̀ ṣeé ṣe kó má jà?
3 Ǹjẹ́ Ogun Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Ṣì Ń Bọ̀ Wá Jà?
4 Àwọn Wo Ló Ń Gbára Dì fún Ogun Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé?
8 Ǹjẹ́ Ó Ṣeé Ṣe Kí Ogun Ọ̀gbálẹ̀gbáràwé Má Jà?
13 Ìmúra àti Ìwọṣọ Ni Kò Jẹ́ Kí N Tètè Rí Òtítọ́
18 Ká Lọ sí Ọjà Ẹja Tó Tóbi Jù Lọ Lágbàáyé
21 Ọjọ́ Lọjọ́ Tí “Olú Ìlú Ọsirélíà Tí Igi Pọ̀ Sí” Jóná
28 Báwo Ni Àǹfààní Tí À Ń Rí Nínú Igbó Ṣe Pọ̀ Tó?
30 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Fi Ìrìn Rírìn Ṣe Eré Ìmárale?
32 ‘Ó Kún Fún Òtítọ́ Ṣíṣeyebíye’
Kí Nìdí Tí Jíjíròrò Nípa Ìbálòpọ̀ Lórí Tẹlifóònù Fi Burú? 10
Lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà nìkan, ọ̀pọ̀ bílíọ̀nù owó dọ́là làwọn iléeṣẹ́ tó ń ṣètò ìjíròrò nípa ìbálòpọ̀ lórí tẹlifóònù ń pa. Kí ni àṣà yìí túmọ̀ sí? Ìpalára wo ló sì ń ṣe fáwọn èèyàn?
Ṣé Bẹ́ẹ̀ Náà Ni Ọtí Àmujù Burú Tó Ni? 22
Ọ̀pọ̀ ló gbà pé kò séwu nínú kéèyàn máa mutí yó bìnàkò lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan. Kí ni Bíbélì sọ nípa rẹ̀?
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Fọ́tò tí U.S. Department of Energy yà; ojú ìwé 2: Ìbúgbàù: Fọ́tò DTRA