Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July-Septemer 2007
Ọgbọ́n Àdámọ́ni Ló Ń Darí Àwọn Ẹyẹ Kí Ló Ń Darí Àwa Èèyàn?
Ọ̀pọ̀ èèyàn kàn ṣáà mọ̀ pé àwọn ń gbé láyé ni, wọn ò mọ ọ̀tún yàtọ̀ sí òsì, wọ́n ò sì mọ ibi táwọn máa bọ́rọ̀ ara àwọn já. Àpilẹ̀kọ yìí á jẹ́ kó o rí bó o ṣe lè jàǹfààní látinú ìtọ́sọ́nà tó dáa jù lọ àti bọ́jọ́ iwájú ẹ ṣe máa dùn bí oyin.
3 Àgbàyanu Lọgbọ́n Tó Ń Darí Àwọn Ẹyẹ
4 Ìtọ́sọ́nà Tó Ju Ọgbọ́n Àdámọ́ni Lọ
8 Jẹ́ Kí Ọlọ́run Ṣamọ̀nà Rẹ Kó O Lè Jogún “Ìyè Tòótọ́”
24 Ṣóòótọ́ Ni Wọ́n Pẹ́ Tó Bẹ́ẹ̀ Láyé?
25 Ṣé Ìlépa Owó Ń Kó Ìdààmú Bá Ẹ?
26 Ṣó O Ti Pinnu Láti Di Ọlọ́rọ̀? Kí Ló Lè Yọrí sí fún Ẹ?
30 Pinnu Láti Fọwọ́ Pàtàkì Mú Ìjọsìn Ọlọ́run
32 “Ohun Tá A Ti Ń Wá Gan-an Nìyí!”
Kí Ló Dé Tí Ẹnikẹ́ni Kì Í Dá sí Mi? 21
Ṣó máa ń ṣe ẹ́ bíi pé o ò rẹ́ni bá rìn, bóyá kó tiẹ̀ dà bíi pé kò sẹ́ni tó rí tìẹ rò, nígbà táwọn míì bá ń ṣe tiwọn láìdá sí ẹ? Kà nípa bí Bíbélì ṣe lè tù ẹ́ nínú àti bó ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.