Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí
Ìwé Ìtàn Bíbélì
© 1978, 2004
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA
Publishers
WATCHTOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF NEW YORK, INC. Brooklyn, New York, U.S.A.
Àlàyé ṣókí la fi kọ àwọn ẹsẹ Bíbélì tá a fà yọ nínú ìwé yìí. A fi èdè tó rọrùn kọ àwọn ẹsẹ Bíbélì náà kó bàa lè yé àwọn ọmọdé. Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó wà ní òpin ìtàn kọ̀ọ̀kan ni ibi tá a ti mú ìtàn náà jáde nínú Bíbélì.
A Tẹ̀ Ẹ́ ní Ọdún 2012
A tẹ ìwé yìí jáde gẹ́gẹ́ bí ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tí à ń fi ọrẹ àtinúwá ṣètìlẹ́yìn fún.