Awọn Koko Ẹkọ Inu Iwe
OJÚ ÌWÉ ÀKÒRÍ
4 1 Ifẹ-Ọkan fun Alaafia ati Àìléwu Kárí-Ayé
13 2 “Ọmọ-Aládé Alaafia” naa Dojukọ Armageddoni
21 3 Iṣakoso “Ọmọ-Aládé Alaafia” Laaarin Awọn Ọta
29 4 “Babiloni” Alailaabo Ni A Ti Ṣedajọ Iparun Fún
38 5 Ìlanilóye fun “Ipari Eto-Igbekalẹ Awọn Nǹkan”
47 6 Ṣíṣọ́nà Ni Akoko “Ipari Eto-Igbekalẹ Awọn Nǹkan”
56 7 Ṣiṣe Iṣiro Lori Ìlò Owó-Àkànlò Kristi
65 8 Nínípìn-ín Ninu “Ayọ̀” “Ọmọ-Aládé Alaafia” Naa
73 9 Majẹmu Ọlọrun Pẹlu “Ọ̀rẹ́” Rẹ̀ Ti Ṣanfaani fun Araadọta Ọkẹ Nisinsinyi
82 10 Ohun Ti Ọlọrun Búra Lati Ṣe fun Araye—Kù Sí Dẹ̀dẹ̀ Nisinsinyi!
90 11 Jerusalemu ti Ilẹ̀-Ayé ní Ìfiwéra Pẹlu Jerusalemu ti Òkè-Ọ̀run
98 12 Majẹmu Titun Ti Ọlọrun Ń Súnmọ́ Àṣeparí Rẹ̀
106 13 “Ọmọ-Aládé Alaafia” naa Yíjú Sí Awọn Wọnni Tí Wọn Wà Lẹ́hìn-Òde Majẹmu Titun Naa
113 14 Lẹhin Majẹmu Titun Naa—Ijọba Ẹlẹgbẹrun Ọdun
121 15 Amápẹẹrẹ Edomu Ṣẹ, ti Òde-Òní Ni A O Mú Kúrò
129 16 “Ogunlọgọ Nla” naa Ń Gba “Òpópó” naa Wá Sinu Ètò-Àjọ Ọlọrun Nisinsinyi
136 17 Fifi Iduroṣinṣin Ranti Ètò-Àjọ Jehofa
144 18 Iduroṣinṣin sí Ètò-Àjọ Ọlọrun Ti A Lè Fojuri Lonii
152 19 “Ogun Ọjọ Nla Ọlọrun Olodumare” Tí Ó Rọ̀dẹ̀dẹ̀
161 20 Idile Eniyan Alayọ Labẹ Ipò-Jíjẹ́ Baba Titun Kan
170 21 A Mú Ọgbà Edeni Padàbọ̀sípò—Yíká-Ayé
180 22 Ọlọrun “Ọmọ-Aládé Alaafia” naa Di “Ohun Gbogbo fun Olukuluku Eniyan”