Àìléwu Kárí-Ayé (ws) Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí Awọn Koko Ẹkọ Inu Iwe Ifẹ-Ọkan fun Alaafia ati Àìléwu Kárí-Ayé “Ọmọ-Aládé Alaafia” naa Dojukọ Armageddoni Iṣakoso “Ọmọ-Aládé Alaafia” Laaarin Awọn Ọta “Babiloni” Alailaabo Ni A Ti Ṣedajọ Iparun Fún Ìlanilóye fun “Ipari Eto-Igbekalẹ Awọn Nǹkan” Ṣíṣọ́nà Ni Akoko “Ipari Eto-Igbekalẹ Awọn Nǹkan” Ṣiṣe Iṣiro Lori Ìlò Owó-Àkànlò Kristi Nínípìn-ín Ninu “Ayọ̀” “Ọmọ-Aládé Alaafia” Naa Majẹmu Ọlọrun Pẹlu “Ọ̀rẹ́” Rẹ̀ Ti Ṣanfaani fun Araadọta Ọkẹ Nisinsinyi Ohun Ti Ọlọrun Búra Lati Ṣe fun Araye—Kù Sí Dẹ̀dẹ̀ Nisinsinyi! Jerusalemu ti Ilẹ̀-Ayé ní Ìfiwéra Pẹlu Jerusalemu ti Òkè-Ọ̀run Majẹmu Titun Ti Ọlọrun Ń Súnmọ́ Àṣeparí Rẹ̀ “Ọmọ-Aládé Alaafia” naa Yíjú Sí Awọn Wọnni Tí Wọn Wà Lẹ́hìn-Òde Majẹmu Titun Naa Lẹhin Majẹmu Titun Naa—Ijọba Ẹlẹgbẹrun Ọdun Amápẹẹrẹ Edomu Ṣẹ, ti Òde-Òní Ni A O Mú Kúrò “Ogunlọgọ Nla” naa Ń Gba “Òpópó” naa Wá Sinu Ètò-Àjọ Ọlọrun Nisinsinyi Fifi Iduroṣinṣin Ranti Ètò-Àjọ Jehofa Iduroṣinṣin sí Ètò-Àjọ Ọlọrun Ti A Lè Fojuri Lonii “Ogun Ọjọ Nla Ọlọrun Olodumare” Tí Ó Rọ̀dẹ̀dẹ̀ Idile Eniyan Alayọ Labẹ Ipò-Jíjẹ́ Baba Titun Kan A Mú Ọgbà Edeni Padàbọ̀sípò—Yíká-Ayé Ọlọrun “Ọmọ-Aládé Alaafia” naa Di “Ohun Gbogbo fun Olukuluku Eniyan”