Atọ́ka
Àbùmọ́ 241
níwájú àwùjọ 168
Àfiwé 257
Àfiwé tààrà 240
Àkójọ ọ̀rọ̀ tó o mọ̀ ságbárí 26, 94 àti 95, 160 sí 165
Alàgbà
dídáhùn ìbéèrè 144
fífún ìjọ ní ìtọ́ni 47 sí 49, 284
gbígbani-níyànjú 265
ìṣírí 268
kíkọ́ni ní ohun tó jóòótọ́ délẹ̀ 225
Àmì ìpíngbólóhùn 84, 97 àti 98
Àmì orí ọ̀rọ̀ àti ọmọ ìdí ọ̀rọ̀ 90
Àpéjọ àyíká, àkànṣe àti àgbègbè 16, 50
Àpèjúwe 53, 57, 240 sí 246, 253 àti 254, 257
Àpẹẹrẹ, fífi lélẹ̀ 61, 195, 229, 267
Àpẹẹrẹ, lílò àwọn 34, 57, 158, 216, 240 sí 246, 257
Àsọtúnsọ 152, 206 sí 208, 210 àti 211, 214
Àsọyé fún gbogbo ènìyàn 52 sí 55, 249
Àṣefihàn 44 àti 45, 49, 78, 82, 141 àti 142, 166
Bí a ṣe máa fi ọ̀rọ̀ sílò 53 àti 54, 60, 157 sí 159, 220, 233
Bíbélì kíkà 9 sí 12, 60, 248 àti 249
Bíbélì—Wo Ìwé Mímọ́
Bí nǹkan ṣe rí lára 115 àti 116, 118 sí 120, 122, 150, 266, 271
Dídánudúró 97 sí 100, 125 àti 126, 152
Dídarí ọ̀nà tí o gbà ń mí 109, 181 sí 185
Dídẹ iṣan tó le tantan 87, 184 àti 185
Dídíwọ̀n àkókò 34, 45, 176, 263 àti 264, 282
Èdè ilẹ̀ òkèèrè
ògbufọ̀ 55
Ẹṣin ọ̀rọ̀ 39 àti 40, 209 sí 211, 218 àti 219, 220 àti 221, 234
Fídíò 249
Fífi ọ̀yàyà sọ̀rọ̀ 118 sí 120, 122 àti 123, 125, 266
Gbígbani-níyànjú 221, 265 sí 267
Gbígbóhùn sókè tàbí rírẹ̀ ẹ́ sílẹ̀ 102, 107 sí 112
Ìbàlẹ̀ ọkàn 43, 125 àti 126, 128, 135 sí 138
Ìbéèrè
bíbéèrè 58 àti 59, 64, 147 àti 148, 187, 216, 222, 231, 236 sí 239, 253 àti 254, 259
dídáhùn 64, 66 sí 70, 143 àti 144, 177 àti 178, 188, 223
Ìbẹ̀rù 43, 125 àti 126, 128, 135 sí 138
Ibi ìkówèésí, Gbọ̀ngàn Ìjọba 34, 37
Ìbọ̀wọ̀fúnni 67 àti 68, 124, 187, 190 sí 193, 200 àti 201, 203 àti 204, 252
gbígbóhùnsókè 109
ìfaraṣàpèjúwe 122
ìtẹnumọ́-ọ̀rọ̀ 103
lílo ìbéèrè 239
ní ìparí ọ̀rọ̀ 221
wíwo ojú àwùjọ 124
Ìdílé
Bíbélì kíkà 11, 60, 248 àti 249
ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì 31 àti 32, 195, 248
Ìdúró ara 109, 133 àti 134, 137
Ìfidánrawò
iṣẹ́ ìwé kíkà 94 àti 95, 130, 263 àti 264
ọ̀rọ̀ sísọ 54 àti 55, 136, 264
Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ 129 àti 130, 166, 175 àti 176, 179 àti 180
Ìgbékalẹ̀ 44 àti 45, 78, 82, 283, 285
Ìgbohùnsílẹ̀
kásẹ́ẹ̀tì àtẹ́tísí 44, 91 àti 92
ohùn ara ẹni 88
Ìjọba náà 58, 209 sí 211, 257, 279 sí 281
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì—Wo Òde ẹ̀rí
Ìkólòlò 95
Ìlapa èrò (ìwé àsọyé)
bí a ṣe ń lò ó 52, 126, 166 sí 169, 176 àti 177, 264
ṣíṣe 39 sí 42, 168 àti 169, 174
tí a tẹ̀ jáde 50, 52 sí 55, 179
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
fíforúkọsílẹ̀ 282
ìgbékalẹ̀ 44 àti 45, 78, 82, 283, 285
ilé ẹ̀kọ́ ìwé kíkà àkànṣe 21 sí 23, 285
ilé ẹ̀kọ́ kejì 285
iṣẹ́ ilé ẹ̀kọ́ 7, 43 sí 49, 78, 284 àti 285
ìwé ilé ẹ̀kọ́, ìlò rẹ̀ 6 àti 7, 282 àti 283
ìwé kíkà lọ́nà tí ó tọ́ 83 sí 85
kókó ìmọ̀ràn ọ̀rọ̀ sísọ 43 sí 45, 78 sí 81, 282 sí 284
olùrànlọ́wọ́ 285
ọ̀rọ̀ jóòótọ́ délẹ̀ 38, 223 sí 225, 242
òde ẹ̀rí 62 sí 64, 167, 186, 202, 217 sí 219, 236 àti 237
Ìpadàbẹ̀wò—Wo Òde ẹ̀rí
Ìpàdé
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn 49, 141 àti 142, 216, 235
Ìpanilẹ́rìn-ín 193
Ìparí ọ̀rọ̀ 177, 208, 220 sí 222
Ìpéye
ìwé kíkà lọ́nà tí ó tọ́ 83 sí 85
ọ̀rọ̀ jóòótọ́ délẹ̀ 38, 223 sí 225, 242
àpèjúwe 240
àsọtúnsọ 206
àtúnyẹ̀wò 31
ẹ̀mí mímọ́ ń ṣèrànwọ́ 19 àti 20, 178
ìfidánrawò 136
lílo ohun tí a lè fojú rí 249 àti 250
Ire ẹlòmíràn jẹni lógún 62 sí 65, 119, 125, 159, 186 sí 189, 198, 218
Ìrísí ojú 116 àti 117, 119, 121 sí 125, 196
Ìró ohùn 119, 137 àti 138, 181 sí 185
Iṣẹ́ ìsìn ní pápá—Wo Òde ẹ̀rí
Ìṣòro ọ̀rọ̀ sísọ 88
Ìtẹ̀síwájú 6 sí 8, 21, 74 sí 77, 271
Ìwádìí 11 àti 12, 29, 33 sí 38, 40, 226, 231 àti 232
fífi ìtẹnumọ́ yíyẹ ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ 104, 150 sí 152
ilé ẹ̀kọ́ ìwé kíkà àkànṣe 21 sí 23, 285
kíkàwé fún àwùjọ 43 àti 44, 85, 97 àti 98, 105, 116, 126 àti 127, 130, 140 àti 141
kíkàwé geerege ní gbàrà tó o bá kọ́kọ́ fojú kàn án 95
mímúra rẹ̀ sílẹ̀ 43 àti 44, 94 àti 95, 98, 105 àti 106, 116, 130, 263 àti 264
títẹnumọ́ àwọn kókó pàtàkì 105 àti 106
Ìwé Mímọ́
fèrò wérò láti inú rẹ̀ 155 àti 156, 231 sí 233, 254
fífi ìtẹnumọ́ kà á 104, 150 sí 152
fífúnni-níṣìírí láti lò ó 145 àti 146
gbígbé ẹ̀kọ́ tí à ń kọ́ni karí rẹ̀ 52 àti 53, 143 àti 144, 148, 224 àti 225, 255 àti 256, 267
ìdí tí ọ̀rọ̀ ẹsẹ Ìwé Mímọ́ fi wáyé 34 àti 35, 148 àti 149, 232, 256
lílò ó bí ó ti yẹ 153 sí 156, 203 àti 204, 256
Ìwọṣọ àti ìmúra 131 sí 134, 190
Kásẹ́ẹ̀tì àtẹ́tísí 44, 91 àti 92
alàgbà—Wo Alàgbà
àpèjúwe 53, 57, 240 sí 246, 253 àti 254, 257
bí a ṣe máa fi ọ̀rọ̀ sílò 53 àti 54, 60, 219, 233
fi ìyàtọ̀ hàn 57 àti 58, 232 àti 233
gbé ọ̀rọ̀ karí Ìwé Mímọ́ 143 àti 144, 148, 224 àti 225, 255 àti 256, 267
ìbéèrè—Wo Ìbéèrè
ìméfò àti èrò tara ẹni 54, 153, 188
ìsọfúnni pọ̀ jù 41, 98, 173, 213 àti 214, 226 àti 227, 234 àti 235, 264
lílo Ìwé Mímọ́ 52 sí 54, 155 àti 156, 231 sí 233, 254
pípanilẹ́rìn-ín 193
rírí i pé ọ̀rọ̀ wọni lọ́kàn—Wo Ọkàn
ṣíṣàlàyé ọ̀rọ̀ lẹ́sẹẹsẹ 41, 170 sí 173, 214
Kókó ìmọ̀ràn ọ̀rọ̀ sísọ 43 sí 45, 78 sí 81, 282 sí 284
Kókó pàtàkì 29, 39 sí 42, 105 àti 106, 146, 168, 212 sí 214
Kókó pàtàkì látinú Bíbélì 47 àti 48
Lílo èdè tó dára 160 sí 165, 176, 198 àti 199, 220
àfiwé tààrà àti àfiwé ẹlẹ́lọ̀ọ́ 240 àti 241
láti fi bí ọ̀rọ̀ rẹ ṣe dáni lójú hàn 195 àti 196
Mímọ bí a ti ń fọ̀rọ̀ wérọ̀ 62 sí 65
Mímúra ọ̀rọ̀ sísọ sílẹ̀ 39 sí 55
àsọyé fún gbogbo ènìyàn 52 sí 55, 249 àti 250
àsọyé tó jẹ́ ìwé kíkà—Wo iṣẹ́ ìwé kíkà
àṣefihàn 44 àti 45, 49, 78, 82, 141 àti 142, 166
ìfidánrawò 46, 54 àti 55, 136, 264
ìgbékalẹ̀ 44 àti 45, 78, 82, 283, 285
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn 49, 141 àti 142, 216, 235
iṣẹ́ ìwé kíkà 43 àti 44, 50, 94 àti 95, 98, 105 àti 106, 116, 127, 130, 263 àti 264
kókó pàtàkì látinú Bíbélì 47 àti 48
ọ̀rọ̀ ní àpéjọ àgbègbè, ti àkànṣe àti àyíká 50
ṣíṣe ìlapa èrò 39 sí 42, 168 àti 169, 174
Òde ẹ̀rí
àtakò 168, 177 àti 178, 195, 199, 253
àwọn tí kò ka Bíbélì kún 68 sí 69, 144, 198 àti 199, 252
bíbẹ̀rẹ̀ ìfọ̀rọ̀wérọ̀ 62 sí 64, 100, 125, 159, 167, 186, 198, 202, 217, 236 àti 237
ìhìn tí a fẹ́ polongo 272 sí 281
ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì 60, 69 àti 70, 188 àti 189, 221 àti 222, 227 àti 228, 235, 238, 248 àti 249, 258 sí 262
ìpadàbẹ̀wò 222
ìparí ọ̀rọ̀ 222
Ó gbéni ró, ó sì ṣàǹfààní 158, 192, 202 sí 205, 266
Ògbufọ̀ 55
Ohun tá a lè fojú rí 247 sí 250
Olùtumọ̀—Wo Ògbufọ̀
Ó yéni 161, 226 sí 229, 232 àti 233, 242 sí 246
Ọgbọ́n inú 69, 192 àti 193, 197 sí 201, 236 àti 237, 242, 251 sí 254
Ọkàn
ìsapá láti rí i pé ọ̀rọ̀ wọni lọ́kàn 33 àti 34, 48 àti 49, 59 àti 60, 166, 238 àti 239, 258 sí 262
mímúra ọkàn ẹni sílẹ̀ 13 àti 14, 27 àti 28, 115 àti 116
Ọ̀nà tí ò ń gbà fèrò wérò 66 sí 70, 192, 198 sí 200, 237 àti 238, 251 sí 254
Ọ̀rọ̀
yíyan èyí tó yẹ 160 sí 165, 195 àti 196, 199, 218 àti 219, 228, 240 àti 241
Ọ̀rọ̀ àìròtẹ́lẹ̀ 177 àti 178, 208
Ọ̀rọ̀ tó jẹ́ ti ìwé kíkà 50
lílo makirofóònù 141
lọ́nà tó o gbà ń sọ̀rọ̀ 130
títẹnumọ́ àwọn kókó pàtàkì 105 àti 106
wíwo ojú àwùjọ 127
Ọ̀rọ̀ tó kún fún ẹ̀kọ́ 33 àti 34, 46, 116, 157 àti 158, 218, 230 sí 233
Ọ̀rọ̀ yọ̀ mọ́ni lẹ́nu 93 sí 96, 196
ìkólòlò 95
àmì orí ọ̀rọ̀ àti ọmọ ìdí ọ̀rọ̀ 90
ìṣòro ọ̀rọ̀ sísọ 88
lọ́nà tó tọ́ 162
orúkọ inú Bíbélì 91
Sísọ̀rọ̀ láìgbáralé àkọsílẹ̀ 50, 114, 129 àti 130, 166, 174 sí 178
Sọ̀rọ̀ bí Ọlọ́run ṣe dá ọ 121, 128 sí 130, 166, 175 àti 176, 179 àti 180, 196
Ṣíṣàlàyé ọ̀rọ̀ lẹ́sẹẹsẹ 41, 170 sí 173, 214
Títẹnumọ́ ọ̀rọ̀ 101 sí 104, 150 sí 152
Wíwo ojú àwùjọ 124 sí 127, 169, 175