Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
“Àwọn tó ń wá Jèhófà yóò yìn ín. Kí wọ́n gbádùn ayé títí láé.”—Sáàmù 22:26.
Ibi Tí A Ti Mú Àwọn Àwòrán: Ojú ìwé 15: Image © Homo Cosmicos/Shutterstock; ojú ìwé 17: NASA, ESA, and the Hubble Heritage Team (STScI/AURA)-ESA/ Hubble Collaboration. Licensed under CC BY 4.0 (http://creativecommons.org/licenses/by/4.0/). Ibi tá a ti rí ìsọfúnni: https://esahubble.org/images/heic0702a/; ojú ìwé 56: Àwòrán látọ̀dọ̀ US Signal Corps/The LIFE Picture Collection via Getty Images; ojú ìwé 76: Château de Versailles, France/Bridgeman Images; ojú ìwé 103 àti 131: Látinú àwòrán NASA/Visible Earth imagery; ojú ìwé 163: © SINGLECELL ANIMATION LLC/Science Source; ojú ìwé 183: Daniel Osterkamp/Moment/Getty Images
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe gbogbo ìwé àti fídíò tá a tọ́ka sí nínú ìwé yìí.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Yoruba (lff-YR)
A tẹ̀ ẹ́ ní July 2024
© 2021 WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA