Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà
Àárọ̀
9:40 Ohùn Orin
9:50 Orin 58 àti Àdúrà
10:00 Ẹ Káàbọ̀, Ẹ̀yin Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà!
10:15 Ẹ Máa Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà
10:30 Jẹ́ Kí Ọmọ Aládé Àlàáfíà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Bó O Ṣe Ń Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà
10:55 Orin 103 àti Ìfilọ̀
11:05 Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà Ò Ní Kọ́ṣẹ́ Ogun Mọ́
11:35 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:05 Orin 79
Ọ̀sán
1:20 Ohùn Orin
1:30 Orin 76
1:35 Ìrírí
1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:15 Àpínsọ Àsọyé: Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà Máa Ń Ran Ara Wọn Lọ́wọ́
• “Ẹ Ṣí Ọkàn Yín Sílẹ̀ Pátápátá”
• Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣe Púpọ̀ Sí I
• Máa Bọlá Fáwọn Àgbàlagbà
3:00 Orin 57 àti Ìfilọ̀
3:10 Àwọn Ọ̀rẹ́ Àlàáfíà Máa Ń Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi
3:55 Orin 45 àti Àdúrà