“Gbọ́ Ohun Tí Ẹ̀mí Ń Sọ fún Àwọn Ìjọ”
Àárọ̀
9:40 Ohùn Orin
9:50 Orin 1 àti Àdúrà
10:00 Báwo La Ṣe Lè “Gbọ́ Ohun Tí Ẹ̀mí Ń Sọ”?
10:15 ‘Àárẹ̀ Ò Mú Ọ’
10:30 “Má bẹ̀rù”
10:55 Orin 73 àti Ìfilọ̀
11:05 ‘O Ò Sẹ́ Ìgbàgbọ́ Rẹ Nínú Mi’
11:35 Ìrìbọmi: Àǹfààní Wo Lo Máa Rí Tó O Bá Ṣèrìbọmi?
12:05 Orin 79
Ọ̀sán
1:20 Ohùn Orin
1:30 Orin 126
1:35 Ìrírí
1:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:15 Àpínsọ Àsọyé: Bá A Ṣe Lè Fi Ìmọ̀ràn Jésù Sílò
• “Ẹ Di Ohun Tí Ẹ Ní Mú Ṣinṣin”
• ‘Máa Ṣọ́ra, Kí O sì Fún Àwọn Ohun Tó Ṣẹ́ Kù Lókun’
• “Mo Ti Ṣí Ilẹ̀kùn Sílẹ̀ Níwájú Rẹ”
3:00 Orin 76 àti Ìfilọ̀
3:10 “Jẹ́ Onítara”
3:55 Orin 129 àti Àdúrà