ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w96 12/15 ojú ìwé 31
  • Atọ́ka Kókó Ẹ̀kọ́ fún Ilé Ìṣọ́ 1996

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Atọ́ka Kókó Ẹ̀kọ́ fún Ilé Ìṣọ́ 1996
  • Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
  • ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN
  • BÍBÉLÌ
  • ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
  • ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
  • ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
  • JÈHÓFÀ
  • JÉSÙ KRISTI
  • LÁJORÍ Ọ̀RỌ̀ Ẹ̀KỌ́ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
w96 12/15 ojú ìwé 31

Atọ́ka Kókó Ẹ̀kọ́ fún Ilé Ìṣọ́ 1996

Tí ń tọ́ka ọjọ́ ìtẹ̀jáde tí ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ fara hàn

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

A Bọ̀wọ̀ fún Ẹ̀tọ́ Àwọn Aláìsàn, 3/15

A Fìdí Ẹ̀tọ́ Ìjọ́hẹn fún Ìtọ́jú Ìṣègùn Múlẹ̀ Lẹ́ẹ̀kan Sí I, 11/15

A Gbé Òmìnira Ìsìn Lárugẹ ní Japan, 11/1

Àlàáfíà Nínú Ayé Onírúkèrúdò, 1/1

Àwọn Àpéjọpọ̀ Onídùnnú-Ayọ̀ Olùyìn, 1/15

Àyíká Ipò fún Ìdàgbàsókè (Equatorial Guinea), 10/15

“Ẹ Máa Mọyì Irú Àwọn Ènìyàn Bẹ́ẹ̀,” 6/15

“Ibo Ni Ṣọ́ọ̀ṣì Yín Tilẹ̀ Wà Ná?” (Mòsáḿbíìkì), 12/15

Ìfẹ̀yìntì Lẹ́nu Iṣẹ́—Ilẹ̀kùn Ṣíṣísílẹ̀ sí Ìgbòkègbodò Ha Ni Bí? 7/15

Ìgbétásì Ìjẹ́rìí ní Ilẹ̀ Gíríìkì, 4/15

Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Gilead, 6/1, 12/1

Ìmúgbòòrò Tí Ó Ní Ìbùkún Jehofa (ìyàsímímọ́ orílé-iṣẹ́), 4/15

Ìrànwọ́ ní Ibi Àwókù, 12/1

Ìwọ́ Ha Jẹ́ Aṣáájú Ọ̀nà Tí Ó Wà Déédéé Bí? 5/15

Jíjẹ́rìí ní Cameroon, 8/15

Jíjẹ́rìí ní Greenland, 6/15

Ọ̀rẹ́ Wọn Pàtàkì Jù Lọ Mú Wọn Dúró, (Czechoslovakia), 3/15

Títan Òtítọ́ Bibeli Kálẹ̀ ní Ilẹ̀ Potogí, 2/15

ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN

1/1, 2/1, 3/1, 4/1, 5/1, 6/1, 8/1, 9/1, 10/1, 12/1

BÍBÉLÌ

Ìjà fún Bibeli Èdè Spanish, 6/1

Ìtàn Àròsọ Ìkún Omi Ti Àkọsílẹ̀ Bíbélì Lẹ́yìn, 9/15

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

A ha fi ẹ̀mí mímọ́ yan àwọn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ di ẹni àmì òróró bí? 8/15

Àwọn Kristẹni ha lè dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini bí? 4/15

Àwọn Kristẹni tí wọ́n ní ìrètí ti ilẹ̀ ayé ha ní ìwọ̀n ẹ̀mí kan náà tí àwọn ẹni àmì òróró ní bí? 6/15

Èé ṣe tí a fi lo toʹte (nígbà náà) láti sọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ ṣáájú àti ohun tí ó ṣẹlẹ̀ tẹ̀ lé e? 7/15

Ẹnì kan ha lè mọ̀ọ́mọ̀ gbàgbé ohun kan bí? (Fip 3:13), 5/1

Ìjọba Ọlọ́run yóò ha dé sórí ilẹ̀ ayé bí? 6/1

Jésù ha mọ ìgbà tí Amágẹ́dónì yóò jà bí? 8/1

Ó ha bọ́gbọ́n mu láti tọ oníṣègùn ìlera ọpọlọ lọ bí? 9/1

Orúkọ olúkúlùkù ìdílé (Efe 3:14, 15), 1/15

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

Báwo Ni Ó Ṣe Yẹ Kí A Gbàdúrà sí Ọlọ́run? 7/15

Bí Àwọn Kristian Olùṣọ́ Àgùntàn Ṣe Ń Ṣiṣẹ́ Sìn Ọ́, 3/15

Di Ìgbọ́kànlé Mú Ṣinṣin Títí Dé Òpin, 5/1

“Ẹ Máa Rántí Àwọn Ọjọ́ Tí Ó Ti Kọjá”—Èé Ṣe? 12/1

Fífi Ìyẹ́ Gun Òkè Bí Idì, 6/15

Fífi Ọwọ́ Títọ̀nà Mú Ọ̀rọ̀ Òtítọ́ 1/1

Gbígbé ní Ìbámu Pẹ̀lú Ẹ̀jẹ́ Ìgbéyàwó Rẹ! 3/1

“Ìgba Dídákẹ́, àti Ìgba Fífọhùn,” 5/15

Ìsìn Kristian Ìjímìjí àti Orílẹ̀-Èdè, 5/1

Ìtùnú, Ìṣírí—Àwọn Ohun Iyebíye Alápá Púpọ̀, 1/15

Ìwọ́ Ha Ń Fara Wé Ọlọ́run Wa Tí Kì Í Ṣojúsàájú Bí? 11/15

Lo Àǹfààní Aláìlẹ́gbẹ́ Yìí! 11/15

Ó Ha Yẹ Kí O Tọrọ Àforíjì Ní Tòótọ́ Bí? 9/15

Ojú Ìwòye Ọlọ́run Nípa Ọtí Líle, 12/15

Ọlọrun, Orílẹ̀-Èdè, àti Ìwọ, 5/1

‘Pípèsè fún Agbo Ilé Ẹni’—Ní Àwọn Ilẹ̀ Tí Ń Gòkè Àgbà, 10/1

Rírí Ayọ̀ Nínú Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn, 2/15

Ṣayẹyẹ Ìṣe Ìrántí Lọ́nà Yíyẹ, 4/1

Wò Kọjá Ohun Tí O Rí! 2/15

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

“Ẹ Ṣiṣẹ́, Kì Í Ṣe fún Oúnjẹ Tí Ń Ṣègbé” (D. Lunstrum), 4/1

Ìrètí Mi Tipẹ́tipẹ́—Láti Má Ṣe Kú Láéláé (H. Priest), 2/1

Jehofa Kò Fìgbà Kankan Pa Wá Tì (N. Dori), 1/1

Jèhófà Ti Jẹ́ Ààbò Mi (P. Makris), 12/1

Jehofa Wà Pẹ̀lú Mi (M. Henning), 6/1

Ó fi Ìrẹ̀lẹ̀ Ṣiṣẹ́ Sin Jèhófà (J. Booth), 6/15

Ohun Tí Ó Lé Ní 50 Ọdún ‘Ríré Kọjá Wá’ (E. Paterakis), 11/1

Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ń Ṣiṣẹ́ “Ìyanu” (T. Héon), 7/1

Pípa Gbogbo Àfiyèsí Pọ̀ Sórí Ẹ̀bùn Náà (E. Michael), 8/1

Ṣíṣiṣẹ́ Sin Jèhófà Gẹ́gẹ́ Bí Ìdílé Tí Ó Wà Níṣọ̀kan (A. Santoleri), 10/1

Ṣíṣiṣẹ́ Sìn Lábẹ́ Ọwọ́ Ìfẹ́ Jehofa (L. Zoumbos), 5/1

Ṣíṣiṣẹ́ Sin Ọlọ́run Tí Ó Ṣeé Gbẹ́kẹ̀ Lé (K. Progakis), 9/1

Wíwà Ní Ìṣọ̀kan Nínú Iṣẹ́ Ìsìn Ní Àwọn Àkókò Dídára àti Búburú (M. àti B. Muller), 3/1

JÈHÓFÀ

Ìdí Tí Ó Fi Lo Orúkọ Títóbi Lọ́lá Jù Lọ Náà, 4/15

Jehofa—Olùfẹ́ Òdodo àti Ìdájọ́ Òdodo, 3/15

Kí Ni Ó Túmọ̀ Sí Láti Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run? 6/15

Kó Ẹrù Ìnira Rẹ Sára Jehofa, 4/1

O Ha Lè Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run Ní Ti Gidi Bí? 6/15

Ọlọ́run Ha Tẹ́wọ́ Gba Gbogbo Onírúurú Ìjọsìn Bí? 7/1

Ọlọrun Bìkítà Nípa Rẹ, 3/1

JÉSÙ KRISTI

Ìhìn Rere Gẹ́gẹ́ Bí Àwọn Ọ̀mọ̀wé Akẹ́kọ̀ọ́jinlẹ̀ Ti Sọ, 12/15

Ìwọ Yóò Ha Ti Dá Mèsáyà Náà Mọ̀ Bí? 11/15

Kíkọbi Ara sí Àwọn Ọ̀rọ̀ Ìdágbére Jesu, 3/15

Òtítọ́ Nípa Jésù, 12/15

LÁJORÍ Ọ̀RỌ̀ Ẹ̀KỌ́ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Aájò Àlejò Kristẹni Nínú Ayé Tí Ó Pín Yẹ́lẹyẹ̀lẹ, 10/1

A Ní Ìdí Láti Ké Jáde fún Ìdùnnú-Ayọ̀, 2/15

A Ń Kọ́ Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Inú Jèhófà, 12/15

A Óò Ha Gbà Ọ́ Là Nígbà Tí Ọlọ́run Bá Gbégbèésẹ̀ Bí? 8/15

Aráyé Nílò Ìmọ̀ Ọlọrun, 1/15

Àwọn Àgùntàn Jehofa Nílò Àbójútó Oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́, 1/15

Àwọn Alábòójútó Arìnrìn Àjò—Àwọn Ẹ̀bùn Nínú Ènìyàn, 11/15

Àwọn Èwe Tí Wọ́n Rántí Ẹlẹ́dàá Wọn, 12/1

Ayọ̀ Ìṣẹ́gun Ìjọsìn Tòótọ́ Sún Mọ́lé, 7/1

Bí Àwọn Alábòójútó Arìnrìn Àjò Ṣe Ń Ṣiṣẹ́ Sìn Gẹ́gẹ́ Bí Olùṣòtítọ́ Ìríjú, 11/15

“Ẹ Dúró Dè Mí,” 3/1

“Ẹ Fẹ́ Òtítọ́ àti Àlàáfíà”! 1/1

‘Ẹ Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́ Nítorí Èmi Jẹ́ Mímọ́,’ 8/1

“Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Ìlà Ipa Ọ̀nà Aájò Àlejò,” 10/1

Ẹ Máa Wo Ọ̀dọ̀ Jèhófà fún Ìtùnú, 11/1

“Ẹ Yin Jah, Ẹ̀yin Ènìyàn!” 4/1

Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Jẹ́ Kí Àwọn Ọmọ Yín Jẹ́ Ìdùnnú Fún Yín, 12/1

Ẹ Yin Ọba Ayérayé! 4/1

Fi Ara Rẹ fún Ìwé Kíkà, 5/15

Gbẹ́kẹ̀ lé Jehofa àti Ọ̀rọ̀ Rẹ̀, 2/1

Gbígbé Ní Ìbámu Pẹ̀lú Òfin Kristi, 9/1

Gbogbo Wa Gbọ́dọ̀ Jíhìn fún Ọlọ́run, 9/15

Ìbùkún Tàbí Ègún—Àwọn Àpẹẹrẹ fún Wa Lónìí, 6/15

Ìbùkún Tàbí Ègún—Yíyàn Kan Wà! 6/15

Ìdílé Jèhófà Ń Gbádùn Ìṣọ̀kan Ṣíṣeyebíye, 7/15

Ìdí Tí Ìjọsìn Tòótọ́ Fi Ń Rí Ìbùkún Ọlọrun Gbà, 4/15

Ìdí Tí Ìsìn Ayé Yóò Fi Dópin, 4/15

Ìjọba Ọlọrun—O Ha Ń Lóye Rẹ̀ Bí? 2/1

‘Ilé Àdúrà fún Gbogbo Àwọn Orílẹ̀-Èdè,’ 7/1

Ìmọ̀ Ẹ̀kọ́—Lò Ó Láti Yin Jehofa, 2/1

Irú Ọmọ Ejò Náà—Báwo Ni A Ṣe Tú U Fó? 6/1

Jehofa Ń Fúnni Ní Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Àlàáfíà àti Òtítọ́, 1/1

Jíjẹ́ Bàbá àti Alàgbà—Ṣíṣe Ojúṣe Méjèèjì, 10/15

Jíjẹ́ Ọkọ àti Alàgbà—Mímú Kí Àwọn Ẹrù Iṣẹ́ Náà Wà Déédéé, 10/15

“Kí Ẹ̀yin Fúnra Yín Di Mímọ́ Nínú Gbogbo Ìwà Yín,” 8/1

Jíjẹ́ Onídùnnú-Ayọ̀ Nísinsìnyí àti Títí Láé, 2/15

Kíkojú Ìpènijà Ìdúróṣinṣin, 3/15

Kí Ni Ó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ Nínú Ìgbésí Ayé Rẹ? 12/15

Kíyè sí Àwọn Adúróṣinṣin! 3/15

Máa Ka Ọ̀rọ̀ Ọlọrun, Kí O Sì Máa Ṣiṣẹ́ Sìn Ín Ní Òtítọ́, 5/15

“Máà Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Kí Ó Dẹ̀,” 3/1

Ǹjẹ́ Kí Jèhófà Lè Sọ Pé O Káre, 9/15

Òfin Kristi, 9/1

Òfin Tí Ó Wà Ṣáájú Kristi, 9/1

Ọlọrun àti Kesari, 5/1

Pa Ìṣọ̀kan Mọ́ ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Wọ̀nyí, 7/15

Sísá Àsálà Lọ Sí Ibi Ààbò Kí “Ìpọ́njú Ńlá” Tó Dé, 6/1

Sísan Ohun ti Kesari Padà fún Kesari, 5/1

Ṣíṣàjọpín Ìtùnú Tí Jèhófà Ń Pèsè, 11/1

Tẹ́ḿpìlì Ńlá Jèhófà Nípa Tẹ̀mí, 7/1

Wíwá Jésù Tàbí Wíwà Níhìn-ín Jésù—Èwo Ni? 8/15

Wíwà Lápọ̀n-ọ́n—Ilẹ̀kùn sí Ìgbòkègbodò Àpọkànpọ̀ṣe, 10/15

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

Ààbò Tòótọ́—Góńgó Àléèbá, 5/15

Ààbò Tòótọ́—Nísinsìnyí àti Títí Láé, 5/15

A Ha Sọ Àsọdùn Nípa Ọrọ̀ Ọba Sólómọ́nì Bí? 10/15

A Ha Ti Ṣe Ẹ̀tanú Sí Ọ Rí Bí? 6/1

Ákúílà àti Pírísílà—Tọkọtaya Àwòfiṣàpẹẹrẹ, 12/15

Àlàáfíà Ha Ṣeé Ṣe Bí? 1/1

Àlá Ha Lè Sọ Nípa Ọjọ́ Ọ̀la Bí? 10/1

A Gbọ́dọ̀ Lálàá, 10/1

A Nílò Àwọn Ọ̀rẹ́ Tòótọ́, 3/15

Ápólò—Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ Olùpòkìkí Òtítọ́ Kristẹni, 10/1

Àwọn Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Láti Ilẹ̀ Ìlérí, 8/15

Àyànmọ́ Ha Ni Ó Ń Darí Ìgbésí Ayé Rẹ Bí? 9/1

Bíbélì Ha Fi Ìgbàgbọ́ Nínú Àyànmọ́ Kọ́ni Bí? 9/1

Dáníẹ́lì Fi Ìdúró Gbọn-in Ṣiṣẹ́ Sin Ọlọ́run, 11/15

Easter Tàbí Ìṣe Ìrántí—Èwo Ni? 4/1

Èé Ṣe Tí Ó Fi Yẹ Kí A Fún Jèhófà Ní Nǹkan? 11/1

Ẹpafíródítù—Òjíṣẹ́ Aṣojú Àwọn Ará Fílípì, 8/15

Ẹ̀tanú Kì Yóò Sí Mọ́! 6/1

Faraday—Onímọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Ẹni Ìgbàgbọ́, 8/1

Fílípì Batisí Ìjòyè Òṣìṣẹ́ Ará Etiópíà Kan, 7/15

Gàmálíẹ́lì—Kọ́ Sọ́ọ̀lù Ará Tásù Lẹ́kọ̀ọ́, 7/15

Gbádùn Ìbádọ́rẹ̀ẹ́ Pípẹ́ Títí, 3/15

Gbígbààwẹ̀ Ha Ti Di Aláìbágbàmu Bí? 11/15

Gbogbo Ìsìn Ni Inú Ọlọ́run Ha Dùn Sí Bí? 9/15

Ìbẹ̀wò sí Ilẹ̀ Ìlérí, 8/15

“Ilé Dáfídì”—Òtítọ́ Ha Ni Tàbí Ìtàn Àròsọ? 10/15

Ìmọ́lẹ̀ Fòpin sí Sànmánì Òkùnkùn, 1/15

Ìrètí Tí Ó Sàn Jù fún Ọkàn, 8/15

Ìròyìn Búburú Tí Ń Pọ̀ Sí I, 4/15

Ìròyìn Rere Ń Bẹ Níwájú! 4/15

Ìtùnú fún Àwọn Tí A Ń Ni Lára, 11/1

Ìtùnú Láàárín Ọdún Tí Ogun Fi Jà, (Bosnia, Croatia), 11/1

Ìwà Ipá Wà Níbi Gbogbo, 2/15

Ìwàláàyè Ha Wà Lẹ́yìn Ikú Bí? 10/15

Ìwàláàyè Lẹ́yìn Ikú—Báwo, Níbo, Nígbà Wo? 10/15

Jíjẹ́ Onídùnnú-Ayọ̀ Nínú Ayé Aláìnídùnnú-Ayọ̀, 1/15

Jona Kọ́ Nípa Àánú Jehofa, 5/15

Kí Ni A Gbọ́dọ̀ Ṣe Láti Rí Ìgbàlà? 2/1

“Kọ́ Wa Bí A Ṣe Ń Gbàdúrà,” 7/15

Lìdíà—Aláájò Àlejò Olùjọ́sìn Ọlọ́run, 9/15

‘Mo Ha Já Mọ́ Nǹkan Kan Lójú Ọlọ́run Bí?’ 3/1

Mose àti Aaroni—Àwọn Onígboyà Olùpòkìkí, 1/15

Nígbà Tí Ìjábá Ti Ìṣẹ̀dá Bá Ṣẹlẹ̀, 12/1

O Ha Ti Rí Ìgbàlà Bí? 2/1

Ohun Tí Àwọn Ẹ̀dá “Tí Wọ́n Gbọ́n Lọ́nà Ìtẹ̀sí Ìwà Àdánidá” Lè Kọ́ Wa, 7/15

Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Ìjọsìn Kirisẹ́ńdọ̀mù 7/1

Òpin Pátápátá sí Ìwà Ipá—Báwo? 2/15

Ọkàn Ha Jẹ́ Àìleèkú Bí? 8/1

Ọlọ́run Ha Béèrè Gbígbààwẹ̀ Bí? 11/15

Ọmọbìnrin Kékeré Fìgboyà Sọ̀rọ̀, 5/15

Padà Di Erùpẹ̀—Báwo? 9/15

Pétérù Wàásù ní Pẹ́ńtíkọ́sì, 9/15

Ta Ni Ó Tọ́ Kí A Pè Ní Rábì? 7/1

Teofilu Ará Antioku, 3/15

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́