Atọ́ka Kókó Ẹ̀kọ́ Fún Ilé Ìṣọ́ 1998
Ó ń tọ́ka sí ìtẹ̀jáde tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Àpéjọpọ̀ “Ìgbàgbọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,” 1/15
Àpéjọpọ̀ “Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Tí Ọlọ́run Fẹ́,” 5/1, 9/1
Àwọn Dókítà, Adájọ́, àti Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, 3/1
Ayẹyẹ Ìgbéyàwó Àrà Ọ̀tọ̀ (Mòsáńbíìkì), 6/15
Dídáàbò Bo Ìhìn Rere Lọ́nà Òfin, 12/1
“Ẹ Di Ohun Tí Ẹ Ní Mú Ṣinṣin” (Gíríìsì), 9/1
Ẹrú Ènìyàn Tàbí Ìránṣẹ́ Ọlọ́run? 3/15
Ẹ̀sìn Kristẹni Lẹ́nu Iṣẹ́—Láàárín Pákáǹleke, 1/15
Gbígbé Ẹ̀tọ́ Yíyàn Lárugẹ (Japan), 12/15
Gbígbé Ìtòsí Òkè Ayọnáyèéfín (Mexico), 8/15
Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Ilé Ẹ̀kọ́ Gilead, 6/1, 12/1
Ìmújáde Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Lédè Yorùbá 7/15
Ìṣẹ̀lẹ̀ Mánigbàgbé Ní Ilẹ̀ Faransé, 7/1
Iṣẹ́ Tí “Kò Lè Ṣàìjèrè Ọ̀wọ̀” (Ítálì), 8/15
Ìwé Kan Tí Ó Wà fún Gbogbo Ènìyàn, Ìwé pẹlẹbẹ, 4/1
Láti Àwọn Ibùgbé Onílé Gogoro ní Àwọn Ìlú Ńlá Títí Dé Àgbègbè Aṣálẹ̀ Gbalasa (Kánádà), 4/15
Mímú Ìhìn Rere Dé Ọ̀dọ̀ Ènìyàn Púpọ̀ Sí I, 2/15
Nígbà Tí Àwọn Ọkàn Yíyigbì Bá Yí Padà (Poland), 10/15
“Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Olùfúnni Ọlọ́yàyà” (ìdáwó), 11/1
ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN
2/1, 3/1, 4/1, 6/1, 7/1, 8/1, 10/1, 11/1
BÍBÉLÌ
Àwọn Ọ̀mọ̀wé Sọ Déètì Mìíràn Tí A Kọ Bíbélì Àfọwọ́kọ, 12/15
“Bíbélì Oníka Kan,” 3/15
Ìtumọ̀ Tí Ó Yí Ayé Padà (Septuagint), 9/15
“Májẹ̀mú Tuntun Alápapọ̀ Èdè Méjì Dídára Jù Lọ,” 2/1
Ǹjẹ́ O Lè Gba Bíbélì Gbọ́? 10/15
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Ìdí tí àwọn àpọ́sítélì kò fi lè wo ọmọdékùnrin kan sàn (Mt 17:20; Mk 9:29), 8/1
Lúùkù 13:24, 6/15
Ṣíṣe àyájọ́ ayẹyẹ ìgbéyàwó, ọjọ́ ìbí, 10/15
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
Àṣà Ìsìnkú, 7/15
Àwọn Àṣà Ìbílẹ̀ àti Àwọn Ìlànà Kristẹni, 10/1
Bọlá fún Iyì Wọn, 4/1
Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ, 7/15
Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Yín! 2/15
Fi Ohun Tí Ó Ṣe Pàtàkì Jù Ṣáájú! 9/1
Gbádùn Ayé Rẹ, 8/15
Gbígbé Àǹfààní Iṣẹ́ Ìsìn Mímọ́ Gẹ̀gẹ̀, 8/1
Ìmoore, 2/15
Kíkẹ́kọ̀ọ́ Láti Inú Àṣìṣe Àtẹ̀yìnwá, 7/1
Máa Tẹ̀ Síwájú Nípa Tẹ̀mí! 10/1
Ìwọ Ha Mọrírì Àwọn Ìbùkún Jèhófà Bí? 1/1
Ó Ha Yẹ Kí N Yáwó Lọ́wọ́ Arákùnrin Mi Bí? 11/15
O Lè Tẹ̀ Síwájú Nípa Tẹ̀mí, 5/15
Owó Orí Ìyàwó, 9/15
“Ọkàn-Àyà Ìgbọràn,” 7/15
Ọnà Ìyíniléròpadà, 5/15
Ṣé Ìyìn Ni Tàbí Ìpọ́nni? 2/1
Ṣọ́ra fún Ríra Ipò! 11/15
Títẹ́wọ́gba Ẹrù Iṣẹ́ Bíbójútó Ìdílé, 6/1
Wíwéwèé Ṣáájú fún Àwọn Olólùfẹ́ Wa, 1/15
Yanjú Ìṣòro ní Ìtùnbí-Ìnùbí, 11/1
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
A Mú Un Dúró La Ọ̀pọ̀ Àdánwò Lílekoko Já (É. Josefsson), 6/1
Ìgbésí Ayé Mi Gẹ́gẹ́ Bí Adẹ́tẹ̀ (I. Adagbona), 4/1
“Inú Rere Rẹ Onífẹ̀ẹ́ Sàn Ju Ìyè” (C. H. Holmes), 2/1
Iṣẹ́ Àyànfúnni Yí Padà Ní Ẹni 80 Ọdún (G. Matthews), 5/1
Kò Sí Ohun Tí Ó Dára Bí Òtítọ́ (G. N. Van der Bijl), 1/1
Látorí Ìjọsìn Olú Ọba sí Ìjọsìn Tòótọ́ (I. Sugiura), 12/1
Mo Dúpẹ́ fún Ogún Kristẹni (G. Gooch), 3/1
Mo Kọ́ Láti Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà (J. Korpa-Ondo), 9/1
Mo Rí Ohun Tó Sàn Ju Wúrà Lọ (C. Mylton), 10/1
“Ohun Tí Ó Yẹ Kí A Ṣe Ni A Ṣe” (G. Couch), 8/1
Wíwu Jèhófà Ni Olórí Àníyàn Mi (T. Neros), 11/1
JÈHÓFÀ
Ó Ha Jẹ́ Ẹni Gidi Sí Ọ Bí? 9/15
Ta Ni Jèhófà? 5/1
JÉSÙ KRISTI
Àwọn Ọjọ́ Tó Lò Kẹ́yìn Lórí Ilẹ̀ Ayé, 3/15
Ìbí Rẹ̀, 12/15
Ìpìlẹ̀ fún Ojúlówó Ìgbàgbọ́, 12/1
Olùṣàkóso “Tí Orírun Rẹ̀ Jẹ́ Láti Àwọn Àkókò Ìjímìjí,” 6/15
LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
A Kórìíra Wọn Nítorí Ìgbàgbọ́ Wọn, 12/1
A Mú Ìdájọ́ Ṣẹ Ní Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Rírẹlẹ̀ Ti Ìpinnu, 5/1
A Óò Dán Ìgbàgbọ́ Kristẹni Wò, 5/15
‘A Óò Gbé Àwọn Òkú Dìde,’ 7/1
Àwọn Àgùntàn Mìíràn àti Májẹ̀mú Tuntun, 2/1
Àwọn Àjọyọ̀ Mánigbàgbé Inú Ìtàn Ísírẹ́lì, 3/1
Báwo Ni Ìgbàgbọ́ Rẹ Nínú Àjíǹde Ti Lágbára Tó? 7/1
Bíbá Ọlọ́run Rìn—Àwọn Ìgbésẹ̀ Àkọ́kọ́, 11/15
Bíbá Ọlọ́run Rìn—Pẹ̀lú Ayérayé Lọ́kàn, 11/15
Dídúró Pẹ̀lú “Ìfojúsọ́nà Oníhàáragàgà,” 9/15
Ètò Àjọ Jèhófà Ń Ti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Lẹ́yìn, 6/15
‘Ẹ Máa Bá A Lọ ní Rírìn ní Ìrẹ́pọ̀ Pẹ̀lú Kristi,’ 6/1
Ẹ Máa Bá A Nìṣó Ní Bíbá Ọlọ́run Rìn, 1/15
Ẹ Máa Ṣiṣẹ́ Ìgbàlà Yín Yọrí! 11/1
Ẹ Má Ṣe Juwọ́ Sílẹ̀ Nínú Eré Ìje fún Ìyè! 1/1
Fara Mọ́ Ìṣàkóso Ọlọ́run Tímọ́tímọ́, 9/1
Fara Wé Àánú Jèhófà, 10/1
Fara Wé Jèhófà—Máa Ṣe Òdodo àti Ìdájọ́ Òdodo, 8/1
Fífún Ìgbọ́kànlé Wa Nínú Òdodo Ọlọ́run Lókun, 8/15
Gbígbèjà Ìgbàgbọ́ Wa, 12/1
Gbígbé Ní Ìbámu Pẹ̀lú Ìyàsímímọ́ Kristẹni ní Òmìnira, 3/15
Ìbùkún Púpọ̀ Sí I Nípasẹ̀ Májẹ̀mú Tuntun, 2/1
Ìgbà àti Àsìkò Wà Lọ́wọ́ Jèhófà, 9/15
Ìgbàgbọ́ àti Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ, 4/15
Ìjójúlówó Ìgbàgbọ́ Rẹ—A Ń Dán An Wò Nísinsìnyí, 5/15
“Ikú Ni A Ó Sọ Di Asán,” 7/1
Ìwé Kan Tí Ó Wà fún Gbogbo Ènìyàn, 4/1
Ìwé Kan Tí Ó Wá Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run, 4/1
Ìyàsímímọ́ àti Òmìnira Ṣíṣe Yíyàn, 3/15
“Jèhófà, Ọlọ́run Aláàánú àti Olóore Ọ̀fẹ́,” 10/1
Jèhófà Jẹ́ Ọlọ́run Májẹ̀mú, 2/1
Jèhófà Ni Ó Yẹ Kí A Gbọ́kàn Lé, 8/15
Jèhófà Ń Mú Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ fún Àwọn Olùṣòtítọ́, 4/15
Jèhófà Ń Mú Ọ̀pọ̀ Ọmọ Wá Sínú Ògo, 2/15
Jèhófà—Orísun Òdodo àti Ìdájọ́ Òdodo, 8/1
Jerúsálẹ́mù—“Ìlú Ńlá ti Ọba Ńlá Náà,” 10/15
Jerúsálẹ́mù Kan Tí Orúkọ Rò, 10/15
Jerúsálẹ́mù—Ó Ha ‘Ré Kọjá Olórí Ìdí Tí O Ní fún Ayọ̀ Yíyọ̀ Bí’? 10/15
“Máa Ja Ìjà Líle fún Ìgbàgbọ́”! 6/1
Mímọrírì Àwọn Ìpéjọpọ̀ Kristẹni, 3/1
“Nípa Ìgbàgbọ́ Ni Àwa Ń Rìn, Kì Í Ṣe Nípa Ohun Tí A Rí,” 1/15
O Ha Mọyì Ètò Àjọ Jèhófà Bí? 6/15
O Ha Ti Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run Bí? 7/15
Òmìnira Ológo fún Àwọn Ọmọ Ọlọ́run Láìpẹ́, 2/15
Ọjọ́ Ìgbàlà Nìyí! 12/15
Ọjọ́ Jèhófà Sún Mọ́lé, 5/1
“Ọkàn Àyà Rẹ Ha Dúró Ṣánṣán Pẹ̀lú Mi Bí?” 1/1
Ṣé Iṣẹ́ Rẹ Yóò La Iná Já? 11/1
Ṣọ́ra fún Àìnígbàgbọ́, 7/15
Ta Ni Yóò “Yè Bọ́”? 5/1
Ti Jèhófà Ni Ìgbàlà, 12/15
Wà Láìséwu Gẹ́gẹ́ Bí Apá Kan Ètò Àjọ Ọlọ́run, 9/1
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Àìní Ìgbọ́kànlé Ń Gbilẹ̀, 8/15
A Óò Ha Máa Fìgbà Gbogbo Nílò Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Bí? 4/15
Àwọn Alátùn-únṣe, 8/15
Àwọn Ènìyàn “Tí Ó Ní Ìmọ̀lára Bí Tiwa,” 3/1
Àwọn Ìsìn Ń Tọrọ Àforíjì, 3/1
Àwọn Maccabee, 11/15
Bánábà—“Ọmọ Ìtùnú,” 4/15
Bẹ́tẹ́lì—Ìlú Ohun Rere àti Búburú, 9/1
Bí Àwọn Áńgẹ́lì Ṣe Lè Ràn Ọ́ Lọ́wọ́, 11/15
Constantine Ńlá, 3/15
Dáríúsì, 11/15
Èé Ṣe Tí Wọ́n Fi Ń Fi Ìsìn Sílẹ̀? 7/1
Ẹ̀mí Nǹkan-Yóò-Dára Tàbí Iyèméjì? 2/1
Fílémónì àti Ónẹ́símù, 1/15
Ìdájọ́ Òdodo fún Kóówá, 8/1
Ìdájọ́ Òdodo—Nígbà Wo àti Lọ́nà Wo? 6/15
Ìdílé Wà Nínú Ewu, 4/1
Ilẹ̀ Ayé—Èé Ṣe Tí Ó Fi Wà Níhìn-ín? 6/15
Jíjọ́sìn Ọlọ́run ní Òtítọ́, 10/1
Mú Sùúrù, 6/1
Nígbà Tí Àwọn Adigunjalè Bá Ṣọṣẹ́, 12/15
Ǹjẹ́ Gbogbo Àlùfáà Gba Ohun Tí Wọ́n Ń Kọ́ni Gbọ́? 10/15
Ǹjẹ́ Ìkú Tí Ń Pa Aráyé Ló Pa Màríà? 8/1
Ǹjẹ́ Kérésìmesì Kò Ti Jẹ́ Ká Gbàgbé Kristi? 12/15
Ǹjẹ́ O Lè Fi Ìyàtọ̀ Sáàárín Ohun Tí Ó Tọ́ àti Ohun Tí Kò Tọ́? 9/1
Ǹjẹ́ O Lè Gbára Lé Ẹ̀rí-Ọkàn Rẹ? 9/1
Ǹjẹ́ O Lóye Ìgbà Tí A Wà Yìí? 9/15
Onígbèéraga Adelé Ọba Kan Pàdánù Ilẹ̀ Ọba Kan (Bẹliṣásárì), 9/15
Òòfà Agbára Ìdánilọ́rùn—Iyì Ènìyàn Tàbí Ògo Ọlọ́run? 2/15
Òtítọ́ Ń Yí Ìgbésí Ayé Pa Dà, 1/1
‘Òtítọ́ Yóò Dá Yín Sílẹ̀ Lómìnira,’ 10/1
Ọjọ́ Ọ̀la Wa Ha Ti Wà Nínú Àkọọ́lẹ̀ Bí? 4/15
Ọrọ̀ Ha Lè Mú Ọ Láyọ̀ Bí? 5/15
“Sọ Àwọn Ènìyàn Gbogbo Orílẹ̀-Èdè Di Ọmọ-Ẹ̀yìn,” 1/1
Ṣé Àìṣèdájọ́ Òdodo Kò Ṣeé Yẹ̀ Sílẹ̀ Ni? 8/1
Ṣé Ilẹ̀ Ayé Fẹ́ Parẹ́ Ni? 6/15
Ṣọ́ra fún Àwọn Olùyọṣùtì! 6/1
Talmud, 5/15
Ta Ní Ń Bẹ Lẹ́yìn Gbogbo Rẹ̀? 5/1
Tíkíkù, 7/15
Títù, 11/15
Wọn Kò Ṣe Orúkọ Lílókìkí fún Ara Wọn, 3/15
Yùníìsì àti Lọ́ísì, 5/15
WỌ́N ṢE ÌFẸ́ JÈHÓFÀ
Ará Samáríà Kan Jẹ́ Aládùúgbò Rere, 7/1
A San Èrè fún Ìwà Títọ́ Jóòbù, 5/1
Èlíjà Gbé Ọlọ́run Tòótọ́ Ga, 1/1
Jésù Rán 70 Ọmọ Ẹ̀yìn Jáde, 3/1
Jésù Wá Àyè Gbọ́ ti Àwọn Ọmọdé, 11/1
Pọ́ọ̀lù Fìgboyà Wàásù, 9/1