Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Bẹ̀ Ọ́ Wò?
Àní nínú ayé onídààmú yìí, ìmọ̀ pípéye láti inú Bíbélì nípa Ọlọ́run, Ìjọba rẹ̀, àti ohun àgbàyanu tó fẹ́ ṣe fún aráyé, lè fún ọ láyọ̀. Bí o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i tàbí kí ẹnì kan kàn sí ọ nílé láti kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́, jọ̀wọ́ kọ̀wé sí Jehovah’s Witnesses, P.M.B. 1090, Benin City 300001, Edo State, Nigeria, tàbí sí àdírẹ́sì tí ó bá yẹ lára èyí tí a tò sí ojú ìwé 2.