Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ Ọdún 2007
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Aláàbọ̀ Ara Ni Síbẹ̀ Ó Ṣiṣẹ́ Ọlọ́run, 4/15
Àpéjọ Àgbègbè “Máa Tọ Kristi Lẹ́yìn!” 6/1
‘Bó Ṣe Dúró Gbọn-in Wú Mi Lórí’ (Jámánì), 10/15
“Ẹ Bá Mi Fìfẹ́ Gba Ẹ̀bùn Yìí” (Rọ́ṣíà), 11/15
“Ẹ̀bùn Tó Ṣeyebíye Gan-an” (Belgium), 12/15
Ẹni Tó Lé Lọ́gọ́rùn-ún Ọdún, 1/15
Ìfẹ́ Ọkàn Adryana, 4/15
Ìgbàgbọ́ Ìyá Borí Ìbànújẹ́ Ọkàn, 8/1
Ilé Ẹjọ́ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn Nílẹ̀ Yúróòpù Dá Wọn Láre (Rọ́ṣíà), 5/15
Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 1/1, 7/1
“Ilé Òkúta” (Sìǹbábúwè), 2/15
Ìròyìn Nípa Ilẹ̀ Áfíríkà, 3/1
Ìṣòro Tá À Ń Borí Kí Ìhìn Rere Lè Dọ́dọ̀ Àwọn Èèyàn (Áfíríkà), 10/15
Lo Àǹfààní Láti Sọ Ohun Tó O Gbà Gbọ́? (ọmọ ilé ìwé), 11/1
Nǹkan Ìyanu Méjì ní Àpéjọ Àgbègbè Kan (Georgia), 8/1
Obìnrin Olóòótọ́ Kan, 2/15
Pápá Tó ‘Funfun Tó Láti Kórè’ (Ilẹ̀ Guajira), 4/15
‘Tèmi Ni Fàdákà, Tèmi Ni Wúrà’ (ọrẹ ìtìlẹ́yìn), 11/1
BÍBÉLÌ
Àkájọ Ìwé Di Ìwé Alábala, 6/1
Àwọn Akọ̀wé Ayé Ọjọ́un, 3/15
Àwọn Àpáàdì Kín Bíbélì Lẹ́yìn, 11/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Aísáyà—Apá Kejì, 1/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jeremáyà, 3/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ìdárò, 6/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ìsíkíẹ́lì, 7/1, 8/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Dáníẹ́lì, 9/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Hóséà, 9/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jóẹ́lì, Ámósì, 10/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ọbadáyà, Jónà, Míkà, 11/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Náhúmù, Hábákúkù, Sefanáyà, 11/15
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Hágáì, Sekaráyà, 12/1
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Málákì, 12/15
Bíbélì Àkọ́kọ́ Lédè Potogí, 7/1
Bíbélì sí Àwọn Èdè Ilẹ̀ Áfíríkà, 1/15
“Ẹ̀bùn Ńlá” Fáwọn Ará Poland, 8/15
Glück Ṣé Iṣẹ́ Takuntakun (Bíbélì lédè Latvia), 6/15
Ǹjẹ́ Jésù Ní Bíbélì? 12/1
Ǹjẹ́ “Májẹ̀mú Láéláé” Wúlò? 9/1
Ǹjẹ́ Ó Wúlò? 4/1
Ó Rọrùn Láti Kà, Àmọ́ Ǹjẹ́ Ó Péye? (100-Minute Bible [Bíbélì ọgọ́rùn-ún ìṣẹ́jú]), 2/1
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒNKÀWÉ
“Aya ọkọ kan” (1Ti 5:9), 4/1
Èdìdì (Iṣi 7:3), 1/1
Ẹrú olóòótọ́ jẹ́ “olóye”? (Mt 24:45), 9/1
Ìgbà wo ni pípe Kristẹni sí ọ̀run dópin? 5/1
Iṣẹ́ ọdẹ àti ẹja pípa, 12/1
Kí ni ‘ogun Ha-Mágẹ́dọ́nì’? (Iṣi 16:14, 16), 2/1
Kí nìdí tí Jésù fi lo ohun tó ní ìwúkàrà (wáìnì) nígbà Ìrántí ikú rẹ̀? 9/15
Kí nìdí tí Sọ́ọ̀lù fi béèrè ọmọ ẹni tí Dáfídì jẹ́? (1Sa 17:58), 8/1
Mélòó lára ẹranko tó mọ́ ló wọnú ọkọ̀ áàkì? 3/15
Nína ife ọtí sókè láti fi kan tẹlòmíì, 2/15
Ǹjẹ́ Ejò inú ọgbà Édẹ́nì ní ẹsẹ̀? (Jẹ 3:14), 6/15
Ǹjẹ́ ó yẹ ká lọ síbi ìgbéyàwó ẹni tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí? 11/15
“Ọkùnrin kan nínú ẹgbẹ̀rún” (Onw 7:28), 1/15
Ṣé ó burú bí Jékọ́bù ṣe pe ara rẹ̀ ní Ísọ̀? (Jẹ 27:18, 19), 10/1
Ta ló ń lọ kórè ọkà bálì ní Nísàn 16? 7/15
Táwọn òbí bá tọ́mọ dáadáa wọn ò ní kúrò lọ́nà Jèhófà? (Òwe 22:6), 6/1
Yẹra fún ohun tó ní èròjà kaféènì? 4/15
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
Àánú, 12/15
Àgbàyanu Ni Ìmọ́lẹ̀ Náà! 3/15
Àwọn Ẹbọ Tínú Ọlọ́run Dùn Sí, 4/1
Àwọn Ìpinnu Tó Ń Mú Kéèyàn Láyọ̀, 10/1
Bìkítà Nípa Àwọn Ẹlòmíì, 6/15
‘Dán Mi Wò,’ 8/15
Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀, 11/1
Ẹ̀yin Èwe Lè Múnú Òbí Yín Dùn, 5/1
‘Fìdí Ìwéwèé Múlẹ̀ Gbọn-in’ (Òwe 16), 5/15
Gbin Ìfẹ́ Ọlọ́run Sọ́kàn Ọmọ, 9/15
Gbóríyìn Fáwọn Èèyàn, 9/1
Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Lọ Sípàdé, 5/15
Ìgbàgbọ́ Nínú Àsọtẹ́lẹ̀, 4/1
Ìlànà Ìwà Híhù, 6/15
Kí Ọmọ Mi Lè Jẹ́ Ẹni Tó Gbẹ̀kọ́, 5/15
Kọ́ Ẹ̀kọ́ Lára Àwọn Ọmọdé, 2/1
Kọ́ Ọmọ Rẹ Láti Jẹ́ Ẹni Àlàáfíà, 12/1
Máa Lọ Síhà Ìmọ́lẹ̀, 10/15
Mú Kí Ìfẹ́ Rẹ Gbòòrò Sí I, 1/1
Ǹjẹ́ Èèyàn Ń Rí Ìtura Lọ́dọ̀ Rẹ? 11/15
Ohun Dáadáa Tó O Lè Fayé Ṣe! 11/15
O Lè Fara Da Àìṣẹ̀tọ́, 8/15
‘Ó Mú Kí A Wá,’ 3/15
‘Ọgbọ́n Jẹ́ fún Ìdáàbòbò’ (Òwe 16), 7/15
Ọkùnrin àti Obìnrin—Ipò Iyì Wọn, 1/15
Sísọ Òótọ́, 2/1
Sún Mọ́ Ọlọ́run, 8/1
Ṣé Ìdádọ̀dọ́ La Fi Ń Di Ọkùnrin? 6/1
Ṣé Ká Máa Jayé Òní Nìkan? 10/15
Tí Nǹkan Ò Bá Rí Bó O Ṣe Rò, 4/15
Tí Ọmọ Bá Kẹ̀yìn sí Ìlànà Jèhófà, 1/15
Wọ́n Láyọ̀ Láti Dúró De Jèhófà, 3/1
‘Wọ́n Ń Gbèrú Nígbà Orí Ewú,’ 9/15
Yẹra Fún Àṣejù, 2/15
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
A Bá A Yọ̀ Pé Ó “Jagun Mólú Pẹ̀lú Ọ̀dọ́ Àgùntàn Náà” (C. Barber), 10/15
Àǹfààní Tí Mo Ní Láti Máa Sin Jèhófà (Z. Stigers), 8/1
À Ń Lọ sí Ayé Tuntun (J. Pramberg), 12/1
A Ò Jẹ́ Kí Ohunkóhun Dí Wa Lọ́wọ́ Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ (L. Davison), 6/1
Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Pátápátá (A. Baxter), 11/1
Ìdí Tí Sísọni Dọmọ Ẹ̀yìn Fi Ń Múnú Mi Dùn (P. Moseley), 2/1
Ìpinnu Tó Tọ́ Yọrí sí Ìbùkún (P. Kushnir), 1/1
Ìṣúra Tá À Ń Wá Kiri Mú Èrè Wá (D. Smith àti D. Ward), 5/1
Jèhófà Gbà Wá Lọ́wọ́ Àwọn Ìjọba Bóofẹ́bóokọ̀ (H. Dornik), 9/1
Mò Ń Retí Ìjọba Tí “Kì Í Ṣe Apá Kan Ayé Yìí” (N. Gutsulyak), 3/1
Ọkùnrin Tó Mọyì Ìwàláàyè Tó sì Nífẹ̀ẹ́ Èèyàn (D. Sydlik), 1/1
Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Nípa Lórí Ìgbésí Ayé Mi (L. Peters), 4/1
JÈHÓFÀ
Ẹni Tó Ṣe Iṣẹ́ Àrà Ìṣẹ̀dá, 8/15
Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fàyè Gba Ìwà Ibi? 9/15
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Ń Wò Ọ́? 8/1
Orúkọ Ọlọ́run Nínú Orin Ilẹ̀ Rọ́ṣíà, 9/1
JÉSÙ KRISTI
Bíbọ̀ Kristi, 3/15
LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
“Àjíǹde Èkíní” Ti Ń Lọ Lọ́wọ́! 1/1
Àǹfààní Wà Nínú Kéèyàn Fara Da Ìjìyà, 8/15
Bá A Ṣe Lè Máa Ṣe Ohun Tó Jẹ́ Ìfẹ́ Ọlọ́run Lónìí, 10/1
‘Baba Yín Jẹ́ Aláàánú,’ 9/15
Báwo La Ṣe Lè Ṣàánú Ọmọnìkejì Wa? 9/15
Bẹ̀rù Jèhófà Káyé Rẹ Lè Dára, 3/1
Bí Àgbàlagbà Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Nìṣó, 6/1
‘Ẹ Dúró Gbọn-in Kí Ẹ sì Rí Ìgbàlà Jèhófà,’ 12/15
Ẹ Jẹ́ Ká Jọ Gbé Orúkọ Jèhófà Ga, 3/1
Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Láti Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, 9/1
“Ẹ Kún Fún Ìdùnnú,” 1/1
“Ẹ Má Ṣe Fi Ibi San Ibi fún Ẹnì Kankan,” 7/1
Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ Ń Sọ̀rọ̀, 10/15
Ẹ Túbọ̀ Máa Fi Ìmọrírì Hàn, 2/1
Ẹ̀yin Aya, Ẹ Ní Ọ̀wọ́ Jíjinlẹ̀ fún Ọkọ́ Yín, 2/15
Ẹ̀yin Obí—Ẹ Kọ́ Ọmọ Yín Tìfẹ́tìfẹ́, 9/1
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Lépa Ohun Tó Máa Gbórúkọ Ọlọ́run Ga, 5/1
Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Mọ Kristi ní Orí Yín, 2/15
‘Ẹ̀yin Ọmọ, Ẹ Jẹ́ Onígbọràn sí Òbí Yín,’ 2/15
Fi Ayé Rẹ Ṣe Ohun Tó Dára Gan-an, 10/1
Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Tẹrí Ba Fáwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Onífẹ̀ẹ́, 4/1
Ìbùkún Làwọn Àgbàlagbà Jẹ́ Fáwọn Ọ̀dọ́, 6/1
Ìjọba Ọlọ́run Tan Mọ́ Ìṣàkóso Jèhófà, 12/1
Jèhófà Jẹ́ Ọlọ́run Tó Mọrírì, 2/1
Jèhófà Mọyì Ìgbọràn Rẹ, 6/15
Jèhófà Ń Kó Wa Yọ Nínú Páńpẹ́ Pẹyẹpẹyẹ, 10/1
Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ìdájọ́ Òdodo, 8/15
Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Kristi àti Ẹrú Olóòótọ́, 4/1
Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Máa Tọ́ Ìṣísẹ̀ Rẹ, 5/1
Ká Máa Lo Ìfaradà Bá A Ṣe Ń Retí Ọjọ́ Jèhófà, 7/15
Kí A Gbé Ìjọ Ró, 4/15
Kí Ìjọ Máa Yin Jèhófà, 4/15
Kí La Lè Ṣe Tí Ẹ̀mí Èṣù Ò Ní Lè Borí Wa? 3/15
Kò Ní Pẹ́ Tí Gbogbo Ìpọ́njú Máa Dópin, 5/15
Kò Sí Ohun Ìjà Tí A Ṣe sí Yín Tí Yóò Yọrí sí Rere, 12/15
Máa Kọ́ni Lóhun Tí Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an, 1/15
Máa Ṣe Ohun Tí Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ Bá Sọ, 10/15
“Máa Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi,” 7/1
Má Ṣe Ya Ohun Tí Ọlọ́run Ti So Pọ̀, 5/1
Ní Ànímọ́ Tí Wàá Fi Lè Sọni Dọmọ Ẹ̀yìn, 11/15
Ǹjẹ́ O Fara Mọ́ Ìṣàkóso Jèhófà? 12/1
Ǹjẹ́ O ‘Ní Ọ̀rọ̀ Lọ́dọ̀ Ọlọ́run’? 8/1
Ǹjẹ́ O Rò Pé O Ti Ṣẹ̀ sí Ẹ̀mí Mímọ́? 7/15
O Gbà Pé Àjíǹde ń Bọ̀ Lóòótọ́? 5/15
Ohun Táwọn Áńgẹ́lì Ń Ṣe Fọ́mọ Aráyé, 3/15
Ọlọ́run ‘Ṣẹ̀dá Wa Tìyanu-Tìyanu,’ 6/15
Ọ̀rọ̀ Jèhófà Kì Í Kùnà, 11/1
Ran Àwọn Ẹlòmíì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Ṣe Ohun Tí Bíbélì Kọ́ni, 1/15
Ṣé Ẹ Óò Máa Bá A Lọ Láti “Rìn Nípa Ẹ̀mí”? 7/15
Ṣé O Ń Múra Sílẹ̀ De Ọjọ́ Jèhófà? 12/15
‘Ṣọ́ra fun Onírúurú Ojúkòkòrò,’ 8/1
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù, Ọ̀gá Nínú Iṣẹ́ Sísọni Dọmọ Ẹ̀yìn, 11/15
Wádìí Àwọn Ohun Ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run, 11/1
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Ámósì—Ń Ká Èso Ọ̀pọ̀tọ́ Ni àbí Ó Ń Rẹ́ Ẹ? 2/1
Ayé Ẹ̀ Dára, 1/1
Básíláì, 7/15
Bèróà, 4/15
Bí Ìwà Ibi Ṣe Bẹ̀rẹ̀, 6/1
Dá Ìjọsìn Tòótọ́ Mọ̀, 3/1
“Ẹlẹ́rìí Aṣeégbíyèlé ní Sánmà,” 7/15
Ẹ̀mí Èèyàn Máa Ń Kú? 7/15
Gbogbo Èèyàn Lè Wà Níṣọ̀kan? 12/1
Gbogbo Ẹ̀yà Wà Níṣọ̀kan, 7/1
Hánà, 3/15
Ìjọba Ọlọ́run Tan Mọ́ Ìṣàkóso Jèhófà, 12/1
Kò Síbi Tó Dà Bí Ilé Ayé, 2/15
Ìsìn Kristẹni Dé Éṣíà Kékeré, 8/15
Ìtùnú fún Àwọn Òbí Tó Ń Ṣọ̀fọ̀, 5/1
Ìwé Kíkọ Ní Ísírẹ́lì Ayé Ọjọ́un, 8/15
Jálẹ̀ Ọdún ní “Ilẹ̀ Dáradára” Náà, 6/15
Jèhófà Mọyì Ìgbọràn Rẹ, 6/15
Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Kristi àti Ẹrú Olóòótọ́, 4/1
Jẹ́fútà, 5/15
Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Máa Tọ́ Ìṣísẹ̀ Rẹ, 5/1
John Milton, 9/15
Jónátánì, 9/15
Kí A Gbé Ìjọ Ró, 4/15
Kí Ìjọ Máa Yin Jèhófà, 4/15
“Kí Ni Òtítọ́?” 10/1
Lúùkù—Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Tó Jẹ́ Ẹni Ọ̀wọ́n, 11/15
Máa Kọ́ni Lóhun Tí Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an, 1/15
Máa Ṣe Ohun Tí Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ Bá Sọ, 10/15
Ǹjẹ́ Ìwà Ìkà Lè Dópin? 4/15
Odò Adágún Sílóámù, 7/15
Ohun Táwọn Áńgẹ́lì Ń Ṣe Fọ́mọ Aráyé, 3/15
‘Olúwa Kí Ló Dé Tó O Dákẹ́?’ (Póòpù ní Auschwitz), 5/15
O Ní Agbaninímọ̀ràn Tó Bá Dọ̀rọ̀ Ìjọsìn? 12/15
O Nírètí Pé Ọ̀la Á Dáa àbí Ò Ń Bẹ̀rù? 5/15
“Ọkọ̀ Òkun Àwọn Ará Kítímù,” 10/15
Ran Àwọn Ẹlòmíì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Ṣe Ohun Tí Bíbélì Kọ́ni, 1/15
Ṣáwọn Kristẹni Lè Ṣayẹyẹ Ìbọ̀rìṣà? 12/15
Ṣé Ẹ̀sìn Tó Bá Wù Ẹ́ Ló Yẹ Kó O Ṣe? 3/1
Ṣé O Ń Múra Sílẹ̀ De Ọjọ́ Jèhófà? 12/15
‘Ṣọ́ra fún Onírúurú Ojúkòkòrò,’ 8/1
Sámúẹ́lì, 1/15
Sírákúsì—Ìlú Tí Ọkọ̀ Pọ́ọ̀lù Ti Dúró, 10/15
Sọ́ọ̀lù Lọ Sọ́dọ̀ Àwọn Ọ̀rẹ́ àti Ọ̀tá Rẹ̀, 6/15
Tẹ̀gbọ́n-Tàbúrò Ló “Kọ́ Ilé Ísírẹ́lì” (Léà, Rákélì), 10/1
Wessel Gansfort—Alátùn-únṣe, 3/1