Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 1, 2009
Ta Ni Ọlọ́run
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
7 Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run Olódùmarè?
9 Ṣé Gbogbo Ẹ̀sìn Ni Inú Ọlọ́run Dùn Sí?
13 Ilé Là Ń Wò Ká Tó Sọmọ Lórúkọ
18 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Ẹ̀rí Tó Ta Yọ Jù Lọ Pé Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Wa
19 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
24 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Jòsáyà Pinnu Láti Ṣohun Tó Tọ́
26 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Ọmọ Títọ́
OJÚ ÌWÉ 10
Ohun Tá A Kọ́ Lọ́dọ̀ Jésù—Nípa Àwọn Àdúrà Tí Ọlọ́run Ń Gbọ́
OJÚ ÌWÉ 16