February 1 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ta Ni Ọlọ́run? Ṣẹ́ni Gidi Kan Ni Ọlọ́run? Ṣé Ọlọ́run Lórúkọ? Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run Olódùmarè? Ṣé Ọlọ́run Bìkítà Nípa Mi? Ṣé Gbogbo Ẹ̀sìn Ni Inú Ọlọ́run Dùn Sí? Ohun Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Ọmọ Títọ́ Ilé Là Ń Wò Ká Tó Sọmọ Lórúkọ Nípa Àwọn Àdúrà Tí Ọlọ́run Ń Gbọ́ Ẹ̀rí Tó Ta Yọ Jù Lọ Pé Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Wa Ǹjẹ́ O Mọ̀? A Fi Tọ̀yàyàtọ̀yàyà Pè Ẹ́ Jòsáyà Pinnu Láti Ṣohun Tó Tọ́ Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà Kí Nìdí Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì Í Fi Í Lo Ère Láti Jọ́sìn Ọlọ́run? Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá?