Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 1, 2011
Kí Ló Lè Mú Kí Ìgbéyàwó Wà Pẹ́ Títí?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Kí Nìdí Tí Ọ̀pọ̀ Ìgbéyàwó Fi Ń Tú Ká?
4 Ojútùú sí Àwọn Àròyé Tó Máa Ń Wáyé
• “Ọ̀rọ̀ èmi àti ẹnì kejì mi kò wọ̀ mọ́”
• “Mi ò rí ohun tí mo fẹ́ nínú ìgbéyàwó yìí mọ́”
• “Ẹnì kejì mi kò ṣe ojúṣe rẹ̀”
• “Ọkọ mi kì í ṣe ojúṣe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aṣáájú”
• “Ìwà tí ẹnì kejì mi ń hù ń múnú bí mi, mi ò lè fara dà á mọ́”
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉE
10 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
14 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Jọ̀wọ́, Ọlọ́run Mi, Rántí Mi fún Rere”
15 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Ta ni Ọlọ́run?
18 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ ní Ohun Tó Tọ́ Nípa Ìbálòpọ̀
25 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Ọlọ́run Fẹ́ràn Rẹ̀, Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ̀ sì Fẹ́ràn Rẹ̀
27 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
21 Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ fún Ọjọ́ Tó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ Nínú Ọdún?