Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 1, 2011
Mẹ́fà Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Tó Ń Ṣẹ Lójú Wa
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ìṣòro Tó Ń Fi Hàn Pé Ìrètí Ń Bẹ
7 Àsọtẹ́lẹ̀ 4. Kò Sí Ìfẹ́ Nínú Ìdílé Mọ́
8 Àsọtẹ́lẹ̀ 5. Pípa Ilẹ̀ Ayé Run
9 Àsọtẹ́lẹ̀ 6. Iṣẹ́ Ìwàásù Tó Kárí Ayé
10 Ohun Tó Dára Jù Ń Bọ̀ Lọ́jọ́ Iwájú!
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
11 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Ipa Tí Ọmọ Lè Ní Lórí Àjọṣe Ọkọ àti Aya
15 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìwà Ibi àti Ìjìyà?
22 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Yẹra fún Ẹgbẹ́ Búburú!
27 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
28 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
31 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Jèhófà Ni Olùṣọ́ Àgùntàn Mi”
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
18 Àwọn Èèyàn Àlàáfíà Gbèjà Orúkọ Rere Wọn
24 Ìgbésí Ayé ní Àkókò Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì—Owó
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Ìsẹ̀lẹ̀ àti Àrùn: © William Daniels/Panos Pictures; Ìyàn: © Paul Lowe/Panos Pictures; Iná epo: U.S. Coast Guard photo