Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 1, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Amágẹ́dọ́nì—Kí Ló Jẹ́? Ìgbà Wo Ni Yóò Dé?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Amágẹ́dọ́nì—Kí Ni Àwọn Èèyàn Kan Sọ Pé Ó Jẹ́?
5 Ohun Tí Amágẹ́dọ́nì Jẹ́ Gan-an
8 Ìgbà Wo Ni Ogun Amágẹ́dọ́nì Yóò Dé?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
10 Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
14 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
15 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Èmi Kì Yóò Gbàgbé Rẹ”
16 Ẹ̀kọ́ Bíbélì
18 Ohun Tó Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀—Kí Lo Lè Ṣe Bí Ọmọ Rẹ Tó Ti Bàlágà Bá Ń Ṣiyè Méjì Nípa Ẹ̀sìn Rẹ?
25 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Ṣé Ayé Yìí Máa Pa Run?
26 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ní Ètò Kan?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
22 Bí Ìgbésí Ayé Ṣe Rí Lákòókò Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì—Àwọn Olórin àti Àwọn Ohun Èlò Ìkọrin
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ibi tí a ti gba àwòrán ẹ̀yìn ìwé: U.S. Department of Energy photograph