Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 1, 2012
© 2012 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Àwọn Obìnrin Jẹ Ọlọ́run Lógún?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ìṣòro Tí Àwọn Obìnrin Ń Bá Yí
4 Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Àwọn Obìnrin Tiẹ̀ Jẹ Ọlọ́run Lógún?
8 Wọ́n Wà Ní Ipò Ọ̀wọ̀ àti Iyì Lójú Ọlọ́run
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉÉ
16 Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Kí Ni Yóò Ṣẹlẹ̀ ní Ọjọ́ Ìdájọ́?
21 Sún Mọ́ Ọlọ́run—“Àwọn Orílẹ̀-Èdè Yóò Ní Láti Mọ̀ Pé Èmi Ni Jèhófà”
22 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
23 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Àwọn Obìnrin Tó Jẹ́ Òjíṣẹ́ Ọlọ́run?
24 Lẹ́tà Kan Láti Ilẹ̀ Gíríìsì
30 Kọ́ Ọmọ Rẹ—Géhásì Fi Ojúkòkòrò Ba Ayé Ara Rẹ̀ Jẹ́
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
12 Mo Ti Wá Mọ Ọlọ́run Tí Mo Ń Sìn Wàyí