September 1 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ìṣòro Tí Àwọn Obìnrin Ń Bá Yí Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Àwọn Obìnrin Tiẹ̀ Jẹ Ọlọ́run Lógún? Wọ́n Wà Ní Ipò Ọ̀wọ̀ àti Iyì Lójú Ọlọ́run Mo Ti Wá Mọ Ọlọ́run Tí Mo Ń Sìn Wàyí Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Kí Ni Yóò Ṣẹlẹ̀ ní Ọjọ́ Ìdájọ́? Inú Rere Ṣe Pàtàkì Lójú Ọlọ́run Sún Mọ́ Ọlọ́run “Àwọn Orílẹ̀-Èdè Yóò Ní Láti Mọ̀ Pé Èmi Ni Jèhófà” Ǹjẹ́ O Mọ̀? Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Àwọn Obìnrin Tó Jẹ́ Òjíṣẹ́ Ọlọ́run? Lẹ́tà Kan Láti Ilẹ̀ Gíríìsì A Lọ Wàásù Ní Ìpẹ̀kun Ilẹ̀ Yúróòpù Níhà Gúúsù Orúkọ Ọlọ́run Di Mímọ̀ Ní Èdè Swahili Kọ́ Ọmọ Rẹ Géhásì Fi Ojúkòkòrò Ba Ayé Ara Rẹ̀ Jẹ́ Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá?