ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w13 10/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Ìsọ̀rí
  • Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
w13 10/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

October 15, 2013

© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.

Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

DECEMBER 2-8, 2013

Ìṣẹ̀dá Ń Jẹ́ Ká Mọ̀ Nípa Ọlọ́run Alààyè

OJÚ ÌWÉ 7 • ORIN: 110, 15

DECEMBER 9-15, 2013

“Ẹ Máa Sìnrú fún Jèhófà”

OJÚ ÌWÉ 12 • ORIN: 62, 84

DECEMBER 16-22, 2013

Ẹ̀kọ́ Tó Wà Nínú Àdúrà Tí Wọ́n Ronú Jinlẹ̀ Gbà

OJÚ ÌWÉ 21 • ORIN: 68, 6

DECEMBER 23-29, 2013

Máa Ṣe Ohun Tí Jésù Sọ Nínú Àdúrà Onífẹ̀ẹ́ Tó Gbà

OJÚ ÌWÉ 26 • ORIN: 57, 56

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

▪ Ìṣẹ̀dá Ń Jẹ́ Ká Mọ̀ Nípa Ọlọ́run Alààyè

Ọlọ́run tí a kò lè fojú rí ló dá ayé àtọ̀run. Ṣó o gbà tọkàntọkàn pé bọ́rọ̀ ṣe rí nìyẹn? Gbogbo èèyàn kọ́ ló gbà bẹ́ẹ̀. Báwo la ṣe lè jẹ́ káwọn èèyàn mọ ẹni tí Ẹlẹ́dàá jẹ́ ká sì mú kí ìgbàgbọ́ tí àwa pẹ̀lú ní nínú rẹ̀ lágbára sí i? A máa rí ìdáhùn sí ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ yìí.

▪ “Ẹ Máa Sìnrú fún Jèhófà”

Bíbélì gba àwa Kristẹni níyànjú pé ká máa sìnrú fún Jèhófà. Àpilẹ̀kọ yìí á jẹ́ ká mọ ètò tó wà fún àwọn ẹrú nínú Òfin Mósè, bá ò ṣe ní jẹ́ kí Sátánì àtàwọn ohun ẹ̀tàn tó wà nínú ayé Èṣù yìí mú wa lẹ́rú àti èrè tó máa jẹ́ tiwa tá a bá sìnrú fún Ọlọ́run láìyẹsẹ̀.

▪ Ẹ̀kọ́ Tó Wà Nínú Àdúrà Tí Wọ́n Ronú Jinlẹ̀ Gbà

▪ Máa Ṣe Ohun Tí Jésù Sọ Nínú Àdúrà Onífẹ̀ẹ́ Tó Gbà

Tá a bá ń ṣàṣàrò lórí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lójoojúmọ́, àdúrà wa máa túbọ̀ nítumọ̀. Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ jẹ́ ká rí i pé èyí rí bẹ́ẹ̀ nínú àdúrà kan táwọn ọmọ Léfì gbà nítorí àwọn èèyàn Ọlọ́run. Àpilẹ̀kọ kejì jíròrò bá a ṣe lè máa ṣe ohun tí Jésù sọ nínú ọ̀kan lára àwọn àdúrà onífẹ̀ẹ́ tó gbà. Àwọn àdúrà méjèèjì yìí kọ́ wa bá a ṣe lè máa fi ìfẹ́ Jèhófà ṣáájú nígbà tá a bá ń gbàdúrà.

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ

3 Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Philippines

17 Ìgbẹ́kẹ̀lé Nínú Jèhófà Mú Èrè Wá

31 Ṣé Wàá Túbọ̀ Máa Kìlọ̀ Fáwọn Èèyàn?

ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Akéde kan ń wàásù ní ìlú kékeré kan tó ń jẹ́ Panajachel, èyí tó wà nítòsí Adágún Atitlan. Yàtọ̀ sí èdè Sípáníìṣì, èdè ìbílẹ̀ mọ́kànlá [11] ni àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní orílẹ̀-èdè Guatemala fi ń wàásù

GUATEMALA

IYE ÈÈYÀN:

15,169,000

AKÉDE:

34,693

ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ:

47,606

[Graph tó wà ní ojú ìwé 2]

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́