ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w13 12/15 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Ìsọ̀rí
  • Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
w13 12/15 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

December 15, 2013

© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.

Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

FEBRUARY 3-9, 2014

Ẹ Má Ṣe “Tètè Mì Kúrò Nínú Ìmọnúúrò Yín”!

OJÚ ÌWÉ 6 • ORIN: 65, 59

FEBRUARY 10-16, 2014

Ṣé Wàá Yááfì Àwọn Nǹkan Torí Ìjọba Ọlọ́run?

OJÚ ÌWÉ 11 • ORIN: 40, 75

FEBRUARY 17-23, 2014

‘Èyí Yóò Jẹ́ Ìrántí fún Yín’

OJÚ ÌWÉ 17 • ORIN: 109, 18

FEBRUARY 24, 2014–MARCH 2, 2014

“Ẹ Máa Ṣe Èyí ní Ìrántí Mi”

OJÚ ÌWÉ 22 • ORIN: 99, 8

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

▪ Ẹ Má Ṣe “Tètè Mì Kúrò Nínú Ìmọnúúrò Yín”!

Ẹ wo bó ti ṣe pàtàkì tó pé ká má ṣe jẹ́ kí wọ́n tàn wá débi tá a fi máa gbà pé àwọn èrò tí ń kọni lóminú àti ìméfò asán jẹ́ òótọ́! Bíbélì fún wa ní àwọn ìkìlọ̀ tó bọ́ sákòókò nípa èyí nínú ìwé Tẹsalóníkà Kìíní àti Ìkejì.

▪ Ṣé Wàá Yááfì Àwọn Nǹkan Torí Ìjọba Ọlọ́run?

Ọ̀pọ̀ nǹkan la gbọ́dọ̀ yááfì ká tó lè máa kọ́wọ́ ti gbogbo nǹkan tó jẹ mọ́ Ìjọba Ọlọ́run. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa kẹ́kọ̀ọ́ látinú àwọn ẹbọ táwọn ọmọ Ísírẹ́lì ìgbàanì rú. A tún máa ṣàgbéyẹ̀wò àpẹẹrẹ ọ̀pọ̀ èèyàn tí wọ́n ń yááfì àwọn nǹkan lóde òní torí kí wọ́n lè máa kọ́wọ́ ti Ìjọba Ọlọ́run.

▪ ‘Èyí Yóò Jẹ́ Ìrántí fún Yín’

▪ “Ẹ Máa Ṣe Èyí ní Ìrántí Mi”

Ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé àkókò kan náà táwọn Júù máa ń ṣe ayẹyẹ Ìrékọjá nínú ọdún ni àwa Kristẹni tòótọ́ náà máa ń ṣe Ìrántí ikú Jésù. Kí nìdí tó fi yẹ ká mọ̀ nípa Ìrékọjá? Báwo la ṣe máa ń mọ ìgbà tó yẹ kí Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa bọ́ sí, kí ló sì yẹ kó túmọ̀ sí fún gbogbo wa?

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ

3 Jèhófà Dáàbò Bò Wọ́n Lábẹ́ Òjìji Àwọn Òkè Ńlá

16 Ǹjẹ́ O Rántí?

27 Bí O Ṣe Lè Fara Da Ikú Ọkọ Tàbí Aya Rẹ

32 Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ 2013

ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Kò rọrùn rárá láti dé ọ̀dọ̀ àwọn tó ń gbé lórí àwọn kopjes (òkè tó kún fún òkúta) yìí. Òkúta gbìǹgbì máa ń lé téńté sórí àwọn míì lára àwọn òkè náà. Àmọ́, àwọn ará máa ń dé ọ̀dọ̀ àwọn tó ń gbé níbi àwọn Òkè Matobo, tó wà ní àgbègbè Matabeleland, lórílẹ̀-èdè Sìǹbábúwè

SÌǸBÁBÚWÈ

IYE ÈÈYÀN:

12,759,565

IYE AKÉDE:

40,034

ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ:

90,894

Ní orílẹ̀-èdè Sìǹbábúwè, àwọn èèyàn fẹ́ràn láti máa ka àwọn ìwé wa gan-an. Ó kéré tán, Ẹlẹ́rìí kọ̀ọ̀kan máa ń fi ìwé ìròyìn mẹ́rìndínlógún [16] síta lóṣooṣù

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 2]

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́