Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 15, 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
NOVEMBER 30, 2015–DECEMBER 6, 2015
Ǹjẹ́ Ò Ń Rí Ọwọ́ Ọlọ́run Nínú Ìgbésí Ayé Rẹ?
OJÚ ÌWÉ 4
DECEMBER 7-13, 2015
OJÚ ÌWÉ 9
DECEMBER 14-20, 2015
OJÚ ÌWÉ 18
DECEMBER 21-27, 2015
OJÚ ÌWÉ 23
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
▪ Ǹjẹ́ Ò Ń Rí Ọwọ́ Ọlọ́run Nínú Ìgbésí Ayé Rẹ?
▪ “Fún Wa Ní Ìgbàgbọ́ Sí I”
Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ máa sọ bí ọ̀rọ̀ wa ṣe jẹ Ọlọ́run lógún àti bá a ṣe lè mọ̀ bẹ́ẹ̀. Ó tún máa jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè rí ọwọ́ Ọlọ́run nínú ìgbésí ayé wa àti bá ò ṣe ní ṣe irú àṣìṣe tí kò jẹ́ káwọn kan rí ọwọ́ rẹ̀. Nínú àpilẹ̀kọ kejì, a máa jíròrò bó ti ṣe pàtàkì tó pé ká ní ìgbàgbọ́ ká lè rí ìgbàlà. A ó sì tún mọ bá a ṣe lè fún ìgbàgbọ́ wa lókun àti bá a ṣe lè máa fi hàn pé a ní ìgbàgbọ́.—Héb. 11:6.
▪ Sin Jèhófà Láìsí Ìpínyà Ọkàn
▪ Máa Ṣàṣàrò Lórí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
Àwọn ohun tí kì í jẹ́ kéèyàn pọkàn pọ̀ kún inú ayé yìí. Kí la lè ṣe ká má bàa jẹ́ kí àwọn ohun tí ò fi bẹ́ẹ̀ ṣe pàtàkì gbà wá lọ́kàn ká lè pọkàn pọ̀ sórí ohun tó ṣe pàtàkì jù, ìyẹn ìjọsìn Ọlọ́run? Tá a bá ń ka Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, báwo la ṣe lè jàǹfààní ní kíkún? A máa ṣàlàyé nínú àwọn àpilẹ̀kọ yìí.
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
3 ‘Ẹ Máa Ka Irú Àwọn Ènìyàn Bẹ́ẹ̀ Sí Ẹni Ọ̀wọ́n’
14 Kò Kábàámọ̀ Ìpinnu Tó Ṣe Nígbà Èwe Rẹ̀
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ: Arákùnrin kan ń darí ìpàdé fún iṣẹ́ ìsìn pápá ní ìlú kékeré kan tó wà ní etíkun, nílùú St. Helens ní erékùṣù Tasmania
TASMANIA, ỌSIRÉLÍÀ
IYE ÈÈYÀN
514,800
IYE ÌJỌ
24
IYE AKÉDE
1,779
IYE ÈÈYÀN TÍ AKÉDE KAN Á WÀÁSÙ FÚN