Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ 2015
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Ǹjẹ́ Ó Dá Ẹ Lójú Pé O Ní Àjọṣe Tó Dán Mọ́rán Pẹ̀lú Jèhófà? 4/15
Ọgọ́rùn-ún Ọdún Tí Ìjọba Ọlọ́run Ti Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣàkóso! 11/15
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
‘Ẹ Máa Ka Irú Àwọn Ènìyàn Bẹ́ẹ̀ Sí Ẹni Ọ̀wọ́n’ (àwọn tó ń ṣèrànwọ́ fún Ìgbìmọ̀ Olùdarí), 10/15
‘Ohunkóhun Ò Gbọ́dọ̀ Dí Yín Lọ́wọ́!’ (àwọn apínwèé-ìsìn-kiri nílẹ̀ Faransé), 11/15
BÍBÉLÌ
Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Tá A Tún Ṣe Lọ́dún 2013, 12/15
Ohun Iyebíye Tí Wọ́n Rí Nínú Pàǹtírí (àjákù òrépèté Rylands), 4/1
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Kí ló fi hàn pé kò pẹ́ táwọn ọmọ Ísírẹ́lì dó ti Jẹ́ríkò tí wọ́n fi ṣẹ́gun rẹ̀? 11/15
Ǹjẹ́ àwọn ìwé ìtàn jẹ́rìí sí i pé Pọ́ńtíù Pílátù gbé láyé rí? 2/15
Ǹjẹ́ ó yẹ kí arábìnrin kan borí rẹ̀ tó bá ń darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? 2/15
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Ìbùkún Jèhófà Mú Kí Ìgbésí Ayé Mi Túbọ̀ Nítumọ̀ (M. Jaracz), 9/15
Jèhófà Fi Àánú Hàn sí Mi Ju Bí Mo Ṣe Rò Lọ (F. Alarcón), 8/1
Mo Ní Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Ọlọ́run àti Pẹ̀lú Màmá Mi (M. Kumagai), 12/15
Ohun Míì Tó Sàn Jù Tá A Fi Ìgbésí Ayé Wa Ṣe (D. àti G. Cartwright), 3/15
Ọ̀pọ̀ Ìbùkún Ní “Àsìkò Tí Ó Rọgbọ àti Ní Àsìkò Tí Ó Kún Fún Ìdààmú” (T. R. Nsomba), 4/15