Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
AUGUST 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ:SEPTEMBER 26–OCTOBER 23, 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
HUNGARY
Inú àwọn ará máa ń dùn tí wọ́n bá ń wàásù fáwọn èèyàn lọ́wọ́ àárọ̀ lágbègbè Odò Danube. Àwọn akéde yìí ń wàásù fún ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ wọn ní gbàgede Vigadó Square nílùú Budapest, orílẹ̀-èdè Hungary
IYE AKÉDE
22,582
AṢÁÁJÚ-Ọ̀NÀ
1,980
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
12,163
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.