Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí
3 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Mo Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Tó Dáa
Ọ̀SẸ̀ NOVEMBER 28, 2016-DECEMBER 4, 2016
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 5-11, 2016
13 Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Rẹ Jó Rẹ̀yìn Tó O Bá Ń Sìn Nílẹ̀ Àjèjì
Lẹ́nu àìpẹ́ yìí, onírúurú àwọn tó ń sọ èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló ń dara pọ̀ mọ́ ìjọ wa. Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ sọ bá a ṣe lè fìfẹ́ hàn sáwọn àjèjì tó ń wà sáwọn ìpàdé wa. Àpilẹ̀kọ kejì jíròrò ohun táwọn tó ń sìn nílẹ̀ àjèjì lè ṣe kí ìgbàgbọ́ wọn má bàa jó rẹ̀yìn.
18 Ǹjẹ́ Ò Ń “Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ọgbọ́n Tí Ó Gbéṣẹ́”?
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 12-18, 2016
21 Bó O Ṣe Lè Mú Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Ìlérí Ọlọ́run Máa Ṣẹ
Ọ̀SẸ̀ DECEMBER 19-25, 2016
26 Máa Lo Ìgbàgbọ́ Nínú Àwọn Ìlérí Jèhófà
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé apá méjì tí ìgbàgbọ́ pín sí bó ṣe wà nínú Hébérù 11:1. Àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ sọ bá a ṣe lè nígbàgbọ́, kí ìgbàgbọ́ wa sì lágbára. Àpilẹ̀kọ kejì jẹ́ ká mọ̀ pé ìgbàgbọ́ kọjá kéèyàn kàn mọ àwọn ìbùkún tí Jèhófà ṣèlérí fún wa.
31 Ǹjẹ́ O Mọ̀?