October Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Yìí ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ Mo Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Tó Dáa “Ẹ Má Gbàgbé Aájò Àlejò” Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Rẹ Jó Rẹ̀yìn Tó O Bá Ń Sìn Nílẹ̀ Àjèjì Ǹjẹ́ Ò Ń “Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ọgbọ́n Tí Ó Gbéṣẹ́”? Bó O Ṣe Lè Mú Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Ìlérí Ọlọ́run Máa Ṣẹ Máa Lo Ìgbàgbọ́ Nínú Àwọn Ìlérí Jèhófà Ǹjẹ́ O Mọ̀?