Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
OCTOBER 2016
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: NOVEMBER 28–DECEMBER 25, 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
LUXEMBOURG
Àwọn arákùnrin yìí ń wàásù fún mẹ́káníìkì kan níbi tí wọ́n ti ń tún mọ́tò ṣe. Ìwé àṣàrò kúkúrú Irú Ìwé Wo Ni Bíbélì Jẹ́? ni wọ́n fẹ́ fún un
IYE ÈÈYÀN
562,958
IYE AKÉDE
2,058
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2015)
3,895
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn, jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, tá a fi àkọtọ́ tó bóde mu kọ, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.