Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ 2016
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
A Mọyì Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Tí Ọlọ́run Ń Fi Hàn sí Wa, July
A Mú Wọn Jáde Kúrò Nínú Òkùnkùn, Nov.
À Ń Láyọ̀ Bá A Ṣe Ń Bá Ọlọ́run Ṣiṣẹ́, Jan.
“Àwa Yóò Bá Yín Lọ” Jan.
Báwo Lo Ṣe Lè Pa Kún Ìṣọ̀kan Tó Wà Láàárín Àwa Kristẹni? Mar.
Báwo Lo Ṣe Máa Ń Ṣèpinnu? May
Bó O Ṣe Lè Mú Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Ìlérí Ọlọ́run Máa Ṣẹ, Oct.
Ẹ Jẹ́ Kí Aráyé Gbọ́ Ìhìn Rere Nípa Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run, July
“Ẹ Jẹ́ Kí Ìfaradà Ṣe Iṣẹ́ Rẹ̀ Pé Pérépéré,” Apr.
“Ẹ Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Ará Tí Ẹ Ní Máa Bá A Lọ”! Jan.
“Ẹ Lọ, Kí Ẹ sì Máa Sọ Àwọn Ènìyàn Gbogbo Orílẹ̀-Èdè Di Ọmọ Ẹ̀yìn,” May
“Ẹ Má Gbàgbé Aájò Àlejò,” Oct.
Ẹ Máa Fìfẹ́ Yanjú Aáwọ̀, May
‘Ẹ Máa Gba Ara Yín Níyànjú Lẹ́nì Kìíní-Kejì Lójoojúmọ́,’ Nov.
Ẹ̀mí Ń Jẹ́rìí Pẹ̀lú Ẹ̀mí Wa, Jan.
Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Káwọn Ọmọ Yín Nígbàgbọ́, Sept.
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Mú Kí Ìgbàgbọ́ Yín Túbọ̀ Lágbára, Sept.
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Báwo Lẹ Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìrìbọmi? Mar.
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ṣé Ẹ Ti Múra Tán Láti Ṣe Ìrìbọmi? Mar.
“Gbígbé Èrò Inú Ka Ẹ̀mí Túmọ̀ Sí Ìyè àti Àlàáfíà,” Dec.
Jèhófà Máa Ń Sẹ̀san fún Àwọn Tó Ń Fi Taratara Wá A, Dec.
Jèhófà Ń Tọ́ Wa Sọ́nà Ká Lè Jogún Ìyè, Mar.
“Jèhófà Ọlọ́run Wa, Jèhófà Kan Ṣoṣo Ni,” June
Jèhófà Pè É Ní “Ọ̀rẹ́ Mi,” Feb.
Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà, Feb.
Jẹ́ Kí ‘Ẹ̀bùn Ọ̀fẹ́ Aláìṣeé-Ṣàpèjúwe’ Ti Ọlọ́run Mú Ẹ Lọ́ranyàn, Jan.
Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin, Feb.
Kí Nìdí Tá A Fi Gbọ́dọ̀ Máa Ṣọ́nà? July
Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ṣètò Ìgbéyàwó? Aug.
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Dá Àwọn Míì Lẹ́kọ̀ọ́? Aug.
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Pé Jọ Láti Jọ́sìn? Apr.
Kó Gbogbo Àníyàn Rẹ Lé Jèhófà, Dec.
Má Ṣe Dá Sí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú Tàbí Ogun, Apr.
Má Ṣe Jẹ́ Kí Àṣìṣe Àwọn Míì Mú Ẹ Kọsẹ̀, June
Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Rẹ Jó Rẹ̀yìn Tó O Bá Ń Sìn Nílẹ̀ Àjèjì, Oct.
‘Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Rọ Jọwọrọ,’ Sept.
Máa Jà Fitafita Kó O Lè Rí Ìbùkún Jèhófà, Sept.
Máa Jẹ Oúnjẹ Tẹ̀mí Tí Jèhófà Ń Pèsè fún Wa Lájẹyó, May
Máa Lo Ìgbàgbọ́ Nínú Àwọn Ìlérí Jèhófà, Oct.
Máa Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, Feb.
Máa Wá Ìjọba Ọlọ́run, Má Ṣe Wá Àwọn Nǹkan, July
Mọyì Jèhófà Tó Jẹ́ Amọ̀kòkò Wa, June
Ǹjẹ́ Bíbélì Ṣì Ń Yí Ìgbésí Ayé Rẹ Pa Dà? May
Ǹjẹ́ Ìmúra Rẹ Ń Fògo fún Ọlọ́run? Sept.
Ǹjẹ́ O Lè Fi Kún Ohun Tó Ò Ń Ṣe Nínú Ìjọsìn Ọlọ́run? Aug.
Ohun Táá Jẹ́ Kí Tọkọtaya Bára Wọn Kalẹ́, Aug.
Ọlọ́run Dá Wa Sílẹ̀ Nípasẹ̀ Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí, Dec.
Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ń Mú Ká Wà Létòletò, Nov.
Ṣé Ọwọ́ Pàtàkì Lo Fi Ń Mú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run? Nov.
Ṣé Wàá Jẹ́ Kí Amọ̀kòkò Ńlá Náà Mọ Ẹ́? June
Tá A Bá Jẹ́ Olóòótọ́, A Máa Rí Ojúure Ọlọ́run, Apr.
Wọ́n Bọ́ Lọ́wọ́ Ìsìn Èké, Nov
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
“Àwọn Tá A Fa Iṣẹ́ Náà Lé Lọ́wọ́” (Àpéjọ Cedar Point, Ohio, lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà), May
“Ẹ Jára Mọ́ṣẹ́, Ẹ̀yin Akéde Ìjọba Ọlọ́run Tó Wà Nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì!!” (1937), Nov.
“Iṣẹ́ Ìwàásù Ń Sèso Rere, Ó sì Ń Fògo fún Jèhófà” (Jámánì, Ogun Àgbáyé Kìíní), Aug.
“Iṣẹ́ Náà Pọ̀” (ọrẹ), Nov.
Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Tọ́ Ẹ Sọ́nà (àwọn ìrírí), Sept.
Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Gánà, July
BÍBÉLÌ
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Ayọ̀ àti Ìbàlẹ̀ Ọkàn fún Ọdún Kan Péré (A. Broggio), No. 1
Inú Mi Kì Í Dùn, Mo Sì Máa Ń Hùwà Ìpáǹle (A. De la Fuente), No. 5
Mo Kọ́ Láti Bọ̀wọ̀ fún Àwọn Obìnrin (J. Ehrenbogen), No. 3
Mo Ṣàṣìṣe Lọ́pọ̀ Ìgbà (J. Mutke), No. 4
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Bí àwọn ará ṣe lè fi ayọ̀ wọn hàn nígbà tí wọ́n bá gba ẹnì kan pa dà, May
Ìgbà wo ni Bábílónì Ńlá mú àwọn èèyàn Ọlọ́run nígbèkùn? Mar.
Kí ló dé táwọn ọ̀tá Jésù fi ranrí mọ́ ọ̀rọ̀ fífọ ọwọ́? (Mk 7:5), Aug.
Ọkùnrin tó ní ìwo yíǹkì akọ̀wé àtàwọn ọkùnrin mẹ́fà tí wọ́n ní ohun ìjà (Isk 9:2), June
Ṣó tọ́ ká fún òṣìṣẹ́ ìjọba kan ní owó tàbí ẹ̀bùn, May
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
“Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ọgbọ́n Tí Ó Gbéṣẹ́,” Oct.
Gbèjà Ìhìn Rere Níwájú Àwọn Aláṣẹ, Sept.
Ìwà Tútù—Ohun Tó Bọ́gbọ́n Mu, Dec.
Jọ́sìn ní Ojúbọ? No. 2
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Olóòótọ́? No. 1
Má Ṣe Máa Ṣàníyàn, No. 1
Máa Fayọ̀ Sin Jèhófà, Feb.
Ran Ìjọ Rẹ Lọ́wọ́, Mar.
Sàn Ju Góòlù (ọgbọ́n Ọlọ́run), Aug.
Ṣé Bí Ìrì Ni Iṣẹ́ Ìwàásù Rẹ Rí? Apr.
Ṣeyebíye Ju Dáyámọ́ǹdì (jíjẹ́ olóòótọ́), June
Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Kò Já Mọ́ Nǹkan Kan, No. 1
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Àwọn Obìnrin Ajẹ́jẹ̀ẹ́ Ìnìkàngbé Di Ìránṣẹ́ Jèhófà (F. and A. Fernández), Apr.
Jèhófà Ti Jẹ́ Kí N Ṣàṣeyọrí (C. Robison), Feb.
Mo Di “Ohun Gbogbo fún Ènìyàn Gbogbo” (D. Hopkinson), Dec.
Mo Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Bó Tilẹ̀ Jẹ́ Pé Mi Ò Ní Apá (B. Merten), No. 6
Mo Láyọ̀ Pé Mò Ń Lo Ara Mi Lẹ́nu Iṣẹ́ Ọlọ́run (R. Parkin), Aug.
Mo Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Tó Dáa (T. McLain), Oct.
JÈHÓFÀ
JÉSÙ KRISTI
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Àfiwé Tó Dára Jù Lọ (fi ìgbàgbọ́ wéra pẹ̀lú Bíbélì), No. 4
Agbára Táwọn Róòmù Fún Ilé Ẹjọ́ Àwọn Júù, Oct.
Àkájọ Ìwé Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, No. 1
Aṣọ àti Aró Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, No. 3
Àwọn olórí àlùfáà tá a mẹ́nu kàn nínú Bíbélì, No. 1
Ẹ̀kọ́ Tá A Rí Kọ́ Lára Àwọn Ẹyẹ, No. 6
Gbígba Ìkìlọ̀, No. 2
Ibo Lo Ti Lè Rí Ìtùnú? No. 5
Ìjà Dáfídì àti Gòláyátì—Ṣé Ó Ṣẹlẹ̀? No. 5
Ìran Tó Sọ Àwọn Tó Ń Gbé Ní Ọ̀run, No. 6
Kí Ló Ń Ṣẹlẹ̀ Nígbà Tá A Bá Kú? No. 1
Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? No. 5
“Mo Múra Tán Láti Lọ” (Rèbékà), No. 3
Nígbà Tí Ẹnì Tó O Nífẹ̀ẹ́ Bá Kú, No. 3
Ǹjẹ́ Ayé Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ìwà Ipá? No. 4
Ohun Táwọn Aṣáájú Ẹ̀sìn Júù Sọ Pé Èèyàn Lè Torí Ẹ̀ Jáwèé Ìkọ̀sílẹ̀, No. 4
Ọ̀rọ̀ Àpọ́nlé Tó Ń Tuni Lára! (“ọmọbìnrin”), Nov.
Ṣé Àwọn Èèyàn Ló Dá Ẹ̀sìn Sílẹ̀? No. 4
Ṣé Gbogbo Àdúrà Ni Ọlọ́run Máa Ń Dáhùn? No. 6
Ṣé Lóòótọ́ Ni Pé Àwọn Kan Máa Ń Fún Èpò Sínú Oko Ẹlòmíì? Oct.
Ṣé Ó Ní Ipò Kan Tá A Gbọ́dọ̀ Wà Ká Tó Lè Gbàdúrà? No. 6
Ṣé Ó Pọndandan Kéèyàn Wà Nínú Ìsìn Kan? No. 4
Tá ni Èṣù? No. 2
“Ti Jèhófà Ni Ìjà Ogun Náà” (Dáfídì), No. 5