Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JULY 2017
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: AUGUST 28–SEPTEMBER 24, 2017
© 2017 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
POLAND
Arákùnrin kan ń wàásù fún ọ̀kan lára àwọn òṣìṣẹ́ inú oko ápù tó wà nílùú Grójec
IYE AKÉDE
119,932
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
50,479
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2016)
190,613
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.