Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
SEPTEMBER 2018
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: OCTOBER 29–DECEMBER 2, 2018
© 2018 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
IRELAND
Àwọn ará máa ń lọ sí erékùṣù Aran, tó wà ní ìwọ̀ oòrùn etíkun Ireland kí wọ́n lè wàásù fáwọn tó ń sọ èdè Irish
IYE AKÉDE
6,747
IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ
3,392
ÀWỌN TÓ WÁ SÍBI ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (2017)
12,082
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.