Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn December
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 416 133.2 10.4 61.0 10.4
Aṣá. Dééd. 15,498 68.4 6.7 26.6 5.8
Aṣá. Olù. 4,748 56.3 4.9 18.3 3.6
Akéde 147,985 11.2 0.9 3.8 1.0
ÀRÒPỌ̀ 168,647 Àwọn Tí A Batisí: 6,668
Ìdí ti iye àwọn akéde fi lọ sílẹ̀ gidigidi ju bí ó ṣe ń rí tẹ́lẹ̀ jẹ nítorí pé ó pẹ́ kí a tó rí ọ̀pọ̀ ìròyìn ìjọ gbà ní ẹ̀ka ọ́fíìsì lẹ́yìn tí a ti ṣàròpọ̀ ìròyìn December. Nítorí náà, a fún gbogbo ìjọ níṣìírí láti rí i dájú pé wọ́n ń fi ìròyìn wọn ránṣẹ́ lákòókò.