Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn March
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 398 133.3 9.7 58.3 10.2
Aṣá. Dééd. 19,295 68.6 5.6 25.9 5.7
Aṣá. Olù. 19,218 53.9 3.5 15.7 3.3
Akéde 158,572 10.7 0.7 3.6 0.9
ÀRÒPỌ̀ 197,483 Àwọn Tí A Batisí: 680
Èyí tí ó ta yọ nínú ìròyìn wa fún oṣù yí ni àwọn aṣáájú ọ̀nà, àròpọ̀ wákàtí, ìpadàbẹ̀wò, àti ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, títí kan iye àwọn tí a batisí. A ní góńgó tuntun àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé tí ó jẹ́ 19,295. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a kò dé góńgó 30,000 aṣáájú ọ̀nà olùrànlọ́wọ́ ní oṣù March, èyí ni iye gíga jù lọ tí a óò ní láti ìgbà tí a ti ní góńgó 22,199 ní April 1990.