Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ìwé Ìjọ
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ ìjọ nínú ìwé Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí.
July 7: Orí 112 àti 113
July 14: Orí 114 àti 115
July 21: Orí 116 sí ìsọ̀rí orí ọ̀rọ̀ “Iṣileti Siwaju Sii Nigba Gbigberalọ”
July 28: Orí 116 láti ìsọ̀rí orí ọ̀rọ̀ “Iṣileti Siwaju Sii Nigba Gbigberalọ” dé ìparí orí náà