Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn January
Av. Av. Av. Av.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 341 136.0 18.0 63.8 11.3
Aṣá. Déédé 19,743 67.3 7.0 24.5 5.4
Aṣá. Olù. 6,859 56.2 4.1 15.4 3.3
Akéde 179,350 10.9 0.9 3.6 0.9
ÀRÒPỌ̀ 206,293 Àwọn Tí A Batisí: 1,318
Inú wa dùn láti ròyìn góńgó tuntun ju ti ìgbàkígbà rí lọ ti 206,293 akéde tí ó ròyìn ní oṣù January. Èyí ni góńgó wa kẹta nínú ọdún iṣẹ́ ìsìn yìí. Àwọn aṣáájú ọ̀nà déédéé 19,743 tí ó ròyìn tún jẹ́ góńgó tuntun kan. Nísinsìnyí, a ti forúkọ àwọn ìjọ 3,999 sílẹ̀.