Àwọn Ìfilọ̀
◼ Àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a óò fi lọni ní October: Àsansílẹ̀ owó fún Ilé Ìṣọ́ tàbí Jí! tàbí fún ìwé ìròyìn méjèèjì. Àwọn ìwé ìròyìn ẹlẹ́ẹ̀mejì lóṣù fún ọdún kan: ₦280. Ẹlẹ́ẹ̀kan lóṣù fún ọdún kan tàbí ẹlẹ́ẹ̀mejì lóṣù fún oṣù mẹ́fà: ₦140. November: Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun. December: Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun àti Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun. January: Ìwé olójú ewé 192 èyíkéyìí tí a tẹ̀ jáde ṣáájú 1985 tí ìjọ ní lọ́wọ́. Àwọn ìjọ tí kò bá ní irú àwọn ìwé bẹ́ẹ̀ lè fi ìwé Ayọ̀—Bi A Ṣe Lè Rí I, Igba Ewe rẹ—Bi o ṣe le Gbadun rẹ Julọ, Igbesi Aye Yii Ha Ni Gbogbo Ohun Ti O Wà Bi?, Iwọ Le Walaaye Titilae ninu Paradise lori Ilẹ Aye lọni. ÀKÍYÈSÍ: Kí àwọn ìjọ tí yóò bá nílò àwọn ìwé ìgbétáásì tí a mẹ́nu kàn lókè yìí béèrè fún wọn lórí Literature Order Form (S-14) olóṣooṣù wọn ti oṣù tí ń bọ̀.
◼ “Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ilé Ẹ̀kọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìṣàkóso Ọlọ́run fún 1999” ni àkìbọnú tí ó wà nínú ìtẹ̀jáde Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa yìí, kí a tọ́jú rẹ̀ fún ìtọ́kasí jálẹ̀ ọdún 1999.
◼ Bí àwọn àkókò tí ìjọ yín máa ń ṣe ìpàdé yóò bá yí padà ní January 1, ó lè pọndandan pé kí ẹ béèrè fún àwọn ìwé ìléwọ́ tuntun láti fi àwọn àkókò ìpàdé tí ó yí padà hàn.
◼ A ti ṣe àwọn àtúnṣe tí ó tẹ̀ lé e yìí sí “Àwọn Ọ̀gangan Àpéjọpọ̀ Àgbègbè ti 1998” tí ó wà nínú àkìbọnú Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa ti May 1998. Kí alábòójútó olùṣalága ìjọ èyíkéyìí tí a ti yí déètì tàbí ọ̀gangan àpéjọpọ̀ wọn padà jọ̀wọ́ ṣètò kí a ṣe ìfilọ̀ ní Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn tí ó tẹ̀ lé e lẹ́yìn tí a bá ti gba Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa yìí.
October 30-November 1, 1998
Jos 1 (Haúsá) NE-3, 4, 6
Ùbogò 1 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-7: F sí O; ME-8; ME-18: A sí O ÀYÀFI Emu Obodoeti àti Emu Uno
November 6-8, 1998
Jos 2 (Gẹ̀ẹ́sì) NE-3, 4, 6 ÀYÀFI Jalingo
Ùbogò 2 (Ísókó) IS-1, 2, 3
November 13-15, 1998
Ùbogò 3 (Ijaw) RV-1, 2
November 20-22, 1998
Ùbogò 4 (Urhobo) U-1: Abbot, Adeniyi, Adidi, Aruakpa, Fonseca, Ganna, Ogorode, Oton, Ugbekoko, àti Urban; U-4
November 27-29, 1998
Agbor 4 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-10: Farm Settlement, Igwete, Ishimili, Ndemili, Ogbe Onishe, Olieogo, àti Umuekum; ME-12: N sí Z; ME-14: Bank Avenue, Efezomor, Ekpon, Ekwuoma, Ogan, Adaigbo, Umudei, Iloakwu, Onije, Ede, àti Egwachime
Ùbogò 5 (Urhobo) U-2: A sí I; U-3: Agadama, Edjekota Ogor, Edjovhe, Ewu, Gbarigolo, Imode, Iwrogoni, Odorubu, Ofoni, Oghio, àti Oginibo; U-5
December 4-6, 1998
Ùbogò 6 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-6: A sí B; ME-7: A sí E; ME-9: Adjomo, Airport, Alegbo, Asheshe Layout, Ayakoromor, Bazunu Layout, àti Enerhen; ME-10: A sí E; ME-18: P sí Z
December 11-13, 1998
Ùbogò 7 (Urhobo) Àwọn ìjọ U-1 tí a kò yàn sí Ùbogò 4; U-2: J sí Z; àwọn ìjọ U-3 tí a kò yàn sí Ùbogò 5
January 8-10, 1999
Ùbogò 8 (Gẹ̀ẹ́sì) ME-6: C sí Z; ME-7: P sí Z; àwọn ìjọ ME-9 tí a kò yàn sí Ùbogò 6; ME-10: F sí Z ÀYÀFI Farm Settlement, Igwete, Ishimili, Ndemili, Ogbe Onishe, Olieogo, àti Umuekum